© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

A
a (art/f)
kan
a (art/m)
kan
abandon (v)
fisílẹ̀
kọ̀ sílẹ̀
abbreviate (v)
gé kúrú
ṣẹ́kù
abbreviation (n)
ìgékúrú
ìẹ́kù
àkékúrú
àkọ̀mọ̀nà
abdomen (n)
ikùn
abduct (v)
gbé sálọ
fa juro
ré lọ
abduction (n)
ìgbésálọ
ìrélọ
abide (v)
bágbé
ability (n)
agbára
óye
ablaze (adj)
gbiná
jó-wòwò
able (adj)
le
lágbára
abnormal (adj)
àèjì
àbàmì
abolish (v)
parẹ́
sọ dasán
sọ dòfo
aborigine (n/f)
onílẹ̀
ọmọ-ìbílẹ̀
aborigine (n/m)
onílẹ̀
ọmọ-ìbílẹ̀
abortion (n)
íẹ́ oyún
ìẹ́yún
ìẹ́nú
about (prep)
nípa ti
ní pasẹ̀
yíká
létí
above (prep)
ga jùlọ
pọ̀ jùlọ
lérí
abroad (adv)
lóde
lẹ́hìn odi
dálẹ̀
kálẹ̀
abrupt (adj)
lójijì
láìmọ̀tẹ́lẹ̀
abscess (n)
eéwo
àléfọ́
ìkójopọ̀ ọyún
absence (n)
àìsí ńlé
absent (adj)
kò sí
kò wà
àìwà
absolutely (adj)
pátápátá
absorb (v)
fàmu
mu tán
abstain (v)
fà sẹ́hìn
takété
sẹ́ ra
abstract (adj)
àfòyemọ́
absurd (adj)
àìbọ́gbọ́nmu
abundance (n)
ọ̀pọ̀
abundant (adj)
lọ́pọ̀lọpọ̀
jiwinni
abuse (n)
èébú
àbùkù
ìlòlọ́nàìtọ́
abuse (v)
lòlọ́nàìtọ́
lò nílòkulò
pèlórúkọkórúkọ
abusive (adj)
èébú
ti èébú
academic (adj)
àjẹmọ́ akadá
academy (n)
ilé ẹ̀kọ́ gíga
ilé ẹ̀kọ́ ìjìnlẹ̀
accelerate (v)
mú yára
mú lọ síwájú
acceleration (n)
ìyára
accelerator (n)
ohun imúyára
accent (n) (language)
àmì ohùn
accept (v)
gbà
tẹ́wọ́gbà
acceptable (adj)
gbígbà
títẹ́wọ́gbà
acceptance (n)
ìtẹ́wọ́gbà
access (n)
àyè
ọ̀nà
accessible (adj)
fùn láyè
accessories (n)
àwọn èròjà
accessory (n)
èròjà
accident (n)
èì
àgbákò
jàmbá
àdébá
accidental (adj)
kíkàgbákò
jàmbá
accidentally (adv)
láìròtẹ́lẹ̀
accommodate (v)
fùn láyè
accommodation (n)
ilé gbígbé
àyè
accompaniment (n)
ìbánikẹ́gbẹ́
àjọrìnpọ̀
accompany (v)
bá-lọ
bá-rìn
bá-kẹ́gbẹ́
accomplish (v)
e parí
e-tán
e àepé
accomplishment (n)
àetán
ìeparí
ìepé
according (prep)
gẹ́gẹ́bí
accordingly (adv)
nítorínáà
bẹ́ẹ̀gẹ́gẹ́
accordion (n)
dùrù afọwọ́tẹ̀
dùrù àfọwọ́lé
account (n) (bank)
owò àpamọ́
ìirò
ìkàsí
accountable (adj)
e ìkàsí
dálẹ́bi
accountant (n/f)
oníirò
akọ̀wé owò
accountant (n/m)
oníirò
akọ̀wé owò
accrue (v)
èrè
èlé
dá-lé
accumulate (v)
kójọ
dá-lé
accumulation (n)
ìkójọpö
àdálé
àkànmọ́
accuracy (n)
ìegẹ́gẹ́
ìedédé
accurate (adj)
dédé
ánsán
accusation (n)
ìbáwí
ẹ̀sùn
ìfisùn
accusative (n) (grammar)
irú èlò gírámà kan
accuse (v)
fisùn
kà sí lọ́rùn
accused (n/f)
arúfin
accused (n/m)
arúfin
ace (n) (card)
ọ̀kan nínú àwọn ìwé pẹlẹbẹ tí a fí iré tàbí tẹ́tẹ́
ache (n)
fí-fọ́
ríro
achieve (v)
e-tán
e-parí
achievement (n)
oríre
àetán
àeparí
acid (adj)
kan
kíkan
acid (n)
ògùn kíkan
ògùn mímú
acknowledge (v)
jẹ́wọ́
gbà
acknowledgement (n)
ìjẹ́wọ́
gbígbà
ìjúbà
acne (n)
eéwo ẹ̀rẹ̀kẹ́
acorn (n)
ìrúgbìn igi óákù
acquaint (v)
fi-hàn
sọ-fún
mú-yé
báló bíi ojúlùmọ̀
acquaintance (n) (know)
ìfihàn
ojúlùmọ̀
ọ̀rẹ́
acquire (v)
jèrè
dé ibẹ̀
acquisition (n)
ohun ìní
èrè
acquit (v)
dásílẹ̀
jọ̀-lọ́wọ́
dáláre
acquittal (n)
ìdásílẹ̀
ìjọ̀lọ́wọ́
ìdáláre
acrobat (n/f)
eléré ìtàkìtì
alágèéré
acrobat (n/m)
eléré ìtàkìtì
alágèéré
acrobatics (n)
eré ìtàkìtì
across (prep)
níbubu
láti ẹ̀gbẹ́ kan dé èkejì
rékọjá
act (n) (action)
ìe
act (v) (play)
eré
action (n)
ìe
ìwà
ìpè-lẹ́jọ́
active (adj)
yára
ìe
aápọn
lakanloju
activist (n/f)
alámúe
activist (n/m)
alámúe
activity (n)
àmúẹ́e
àmúe-iẹ́
ìyára
apọ́n
actor (n)
òeré
actress (n)
òeré
eléré
actual (adj)
gangan
àtọwọ́dá
actually (adv)
nítòótọ́
pàápàá
gan
acupuncture (n)
ìfi abẹ́rẹ́ gún ní lára
irú ìwòsàn ìlù ìwọ òrùn
acute (adj)
mímú
le
lóró
adamant (adj)
lórí-kunkun
ní dandan
adapt (v)
mú yẹ
bádọ́gba
adaptable (adj)
ní mímúye
adapter (n)
alámùúye
ohun tí mú bádọ́gba
add (v)
ròmọ́
fikún
fi-sí
bùkún
addict (n/f)
ẹnití ó fẹ́ràn nkan láfẹ̀ẹ́jù
addict (n/m)
ẹnití ó fẹ́ràn nkan láfẹ̀ẹ́jù
addiction (n)
ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́
àfẹ́sódì
ìfẹ́ ìpanilára
addition (n) (math)
àròpọ́
ìfikún
ìrópọ̀
àrolu
additional (adj)
àfikún
rírọ́pọ̀
rírolu
additive (n)
àfikún
àlúmọ́
address (n) (place)
ibi ìkọ̀wé sí
address (n) (speech)
ìbá-sọ̀rọ̀
ọ̀rọ̀ sísọ
address (v) (people)
bá-sọ̀rọ̀
sọ-sí
address (v) (place)
kọ̀wé-sí
adequate (adj)
tó-fún
adhesive (adj)
ohun tí a lè fi lẹ̀ nkan
ìlẹ̀mọ́
àlẹ̀mọ́
adjacent (adj)
nítòsí
lágbègbè
lẹ́ẹ̀bá
adjective (n)
ọ̀rọ̀ àpéjúwe
adjourn (v)
sísún ìpàdé síwájú
yíyẹ̀ sí àkókò míràn
adjust (v)
tò-lẹ́sẹsẹ
tún e
adjustable (adj)
títò-lẹ́sẹsẹ
títún e
adjustment (n)
ìtúne
ìtòlẹ́sẹsẹ
administer (v)
e ìpínfúnni
pín-fún
administration (n)
ìpínfúnni
administrator (n/f)
olùpínfúnni
olútọ́jú
administrator (n/m)
olùpínfúnni
olútọ́jú
admirable (adj)
níyìn
yani-lẹ́nu
tayọ
admiral (n)
olórí ọkọ́ ojú omi
olórí ọkọ̀-ogun
admiration (n)
ìyìn
ìjọni-lòjú
ìyani-lẹ́nu
admire (v)
yìn
jọni-lòjú
yani-lẹ́nu
admissible (adj)
íegbàwọlé
ie ìjẹ́wọ́
íe gbígbà
admission (n) (confession) jíjẹ́wọ́
gbígbà
admission (n) (entrance)
ìwọlé
ìgbàsílẹ̀
admit (v) (allow)
gba-wole
gbà-sílë
admit (v) (confess)
ìjẹ́wọ́
admittance (n) (entry)
ìgbàsílẹ̀
ìwọlé
adolescence (n)
ìgbà ọ̀dọ́
adolescent (n/f)
ọ̀dọ́mọbìnrin
adolescent (n/m)
ọ̀dọ́mọkùnrin
adopt (v)
sọdọmọ
gbàtọ́
fiọmọ
gbàọ́mọ
adopted (adj)
sọdọmọ
adoption (n)
ìsọdọmọ
àgbàọ́mọ
adorable (adj)
ìbu-ọlá fùn
ìjúbà
adore (v)
júbà
bu-ọlá fùn
yìn lóògo
fìfẹ̀ fún
adorn (v)
e-lóge
e lọ́ọ̀ọ́
adrift (adj)
gbà-lọ
gbá kiri
adult (adj)
àgbàlá
àgbàlagbà
adult (n)
àgbàlá
àgbàlagbà
adultery (n)
ìwà-panágà
ìwà àgbèrè
advance (v)
tẹ̀-síwájú
lọ-síwájú
gbéga
sanwó ajú
advanced (adj)
ẹ̀mí ìtẹ̀-síwájú
ẹ̀mí ìlọ-síwájú
advancement (n)
ìlọsíwájú
títẹ̀síwájú
advantage (n)
ànfàní
ìrọrùn
èrè
ìfà
advantageous (adj)
rọrùn
ànfàní
lérè
adventure (n)
ìrìn akọ
adventurer (n/f)
adágbà
adáwọ́lé
adventurer (n/m)
adagba
adawole
adverb (n)
ọ̀rọ̀ àpọ́nlé
adversary (n)
ọ̀tá
olódì
aodì
adverse (adj)
lòdìsí
ì
advertise (v)
polówó
sọ-fún
kéde
ròhìn
advertisement (n)
ìpolówó
ìròhìn
ìsọfún
ìkéde
advertising (n)
pípolówó
kíkéde
advice (n)
ìmọ̀ràn
ìfọ̀nàhàn
advisable
tító fún ímọ̀ràn
yẹ ní íe
advise (v)
kọ́
fọ̀nàhàn
íníyè
bá-rò
adviser (n/f)
olùkọ́
olùfọ̀nàhàn
onímọ̀ràn
olọ́rọ̀-ẹni
adviser (n/m)
olùkọ́
olùfọ̀nàhàn
onímọ̀ràn
olọ́rọ̀-ẹni
advocate (v)
gbàwí
gbà
gbèjà
aerial (adj)
lójú ọ̀run
lójú súnmà
affair (n) (business)
iẹ́
ọ̀ràn
affect (v)
mú-lọ́kàn
wú-lórí
kàn
gbọ́
affected (adj)
ìmúlọ́kàn
ìwúlórí
kíkàn
affection (n)
ìfẹ́
ìwúrí
ọkàn-ìfà
affectionate (adj)
ní ìfẹ́
kún fún ìfẹ́
affidavit (n)
ìbúra lórí ìwé
affirm (v)
tẹnumọ́
níní-hẹn
affirmative (adj)
gbólóhùn ìjẹ́hẹn
títẹnumọ́
affix (v)
lẹ̀mọ́
fi-mọ́
so-mọ́- lẹ́hìn
afflict (v)
pọ́n-lójú
jẹ-níyà
yọ-lẹ́nu
e-níẹ̀ẹ́
affliction (n)
ìpọ́njú
ìjìyà
ìdálóró
affluence (n)
ìànsí
ọ̀pọ̀
ọrọ̀
affluent (adj)
ọlórọ̀
íànsí
ọ̀pọ̀
afford (v)
e
fún
náwó
ní agbára láti e nkan
afloat (adv)
lófòó
fó lójú omi
afraid (adj)
bẹ̀rù
fòiyà
Africa (n)
ilẹ̀ Áfríkà
ilẹ́ àwón ènìà dúdú
African (adj)
tíí e ti Áfríkà
ti orílẹ̀ èdè Áfríkà
African (n/f)
ọmọbìnrin ilẹ̀ Áfríkà
African (n/m)
ọmọkùnrin ilẹ̀ Áfríkà
after (adv)
lẹ́hìn
after (prep)
tẹ́lẹ̀
afternoon (n)
ọ̀sán
ọ̀jọ́rọ̀
afterwards (adv)
lẹ́hìnnáà
nígbẹ̀hìn
again (adv)
lẹ́kèejì
tún
lẹ́kànsi
against (prep)
lòdìsí
ò-dìsí
dojúkọ
age (n)
àkókò
ìgbà
ọjọ́ orí
ìran
age (v)
dàgbà
darúgbó
sọ di arúgbó
yewú
agency (n)
ìojúẹni
agenda (n)
ètò ìpàdé lẹ́sẹsẹ
agent (n/f)
aojúẹni
agbàe
aelédeni
agent (n/m)
aojúẹni
agbàe
aelédeni
aggravate (v)
dánúbí
bí-nínú
sọdi búburú sí
aggravating (adj)
dídánúbí
aggravation (n)
ìdánúbí
ìmúbínú
ìsọdi búburú sí
aggression (n)
ìfínràn
ìtètètọ́
wíwá-ìjà
aggressive (adj)
ìwà ìfínràn
ìwà títọ́ni
aggressor (n/f)
olùwájà
òfínràn
atọ́ni
aggressor (n/m)
olùwájà
òfínràn
atọ́ni
agitate (v)
rú sókè
sọ̀rọ̀ lé lórí
ago (adv)
kọjá
sẹ́hìn
àtijọ́
agony (n)
ìrora
ìwáiyà-ìjà
agree (v)
finúọ̀kan
àdéhùn
fohùnọ̀ka
bárẹ́
agreeable (adj)
yẹ
dára
jọjú
wọ̀
agreed (adj)
gbígbà
nísọ̀kàn
ìàdéhùn
bíbárẹ́
agreement (n)
àdéhùn
ìfinúọ̀kan
ìfọwọ́sowọ́
ìpínhùn
agricultural (adj)
nípa ìe àgbẹ̀
okoíe
agriculture (n)
okoríro
ìmọ̀ nípa ọ̀̀gbìn
ìẹ àgbẹ̀
ahead (adv)
níwájú
aid (n)
ìrànlọ́wọ́
ìtìlẹ́hìn
aid (v)
ràn-lọ́wọ́
tì-lẹhìn
aide (n/f)
olùrànlọ́wọ́
olùtìlẹ́hìn
aide (n/m)
olùrànlôwô
olùtìlẹ́hìn
ailment (n)
àìsàn
àìlera
àrùn
aim (n)
ohun àfojúsí
ohun tí à nwò níwájú
aim (v)
wọ́n-wò
fẹ́
fojúsí
air (n)
òfúrufú
afẹ́fẹ́
ojú sánmà
air force (n)
bàlúù alágbára ogun
ọmọ ogun òfúrufú
air raid (n)
ìjà àfi bálúù jà
aircraft (n)
ọkọ̀ ìjà òfúrufú
airline (n)
ẹgbẹ́ oníbàlúù
airmail (n)
ọ̀nà ìfìwé ránẹ́ kíákíá
airplane (n)
bàlúù
ọkọ̀ òfúrufú
airport (n)
pápá bàlúù
pápá ọkọ̀ òfúrufú
aisle (n)
ọ̀nà àrín àga títò ní ibùjókọ̀ó òwòrán
alarm (n)
ìdánijí
ìdágìrì
alarm clock (n)
ago ìdá-ni-níjí
alarming (adj)
dídánijí
dídágìrì
album (n) (folder)
ìwé ìpamọ́ àwòrán
alcohol (n)
ọtí
ọtí líle
alcoholic (n/f)
ọ̀mùtí
alcoholic (n/m)
ọ̀mùtí
alcoholism (n)
ìmutí
mímutí
alert (adj)
óra
yára
dárayá
alert (n) (military)
iyàrá ológun
ìmúra-ogun
alert (v)
e ìóra
yára
yáwọ́
alias (n)
orúkọ mìíràn
alibi (n)
ẹ̀rí àbò ìgbara ẹni là
alienate (v)
fi lé ẹlòmíràn lọ́wọ́
mú ìfẹ́ ẹni kúrò lí ọkàn
alienation (n)
mìmú ìfẹ́ ẹni kúrò lí ọkàn
alight (v)
sọ̀-kalẹ̀
ba lẹ̀
align (v)
tò dọ́gba
ba dọ́gba
alike (adj)
jọra
bákannáà
alimony (n)
owó ìtọ́jú
alive (adj)
láàyè
all (adj)
gbogbo
olúkúlùkú
allegation (n)
ìtẹnumọ́
àwáwí
ẹ̀sùn
allegedly (adv)
títẹnumọ́
allegiance (n)
ìsìn-ọba
ìtẹríba
ìtúbá-fọ́ba
allergic (adj)
tí kò bálára mu
allergy (n)
ohun àìbánilára mu
alley (n)
ọ̀nà híhá
ọ̀nà tọ́rọ́
alliance (n)
ìbáọ̀rẹ́
láarín orílẹ̀ èdè nípa májẹ̀mú
allied (adj)
bíbáọ̀rẹ́
alligator (n)
ọ̀nì
alégbà
ẹranko jomijòkè
allocate (v)
fi-sípò
pín fún
allocation (n)
ìpín
ipò
ìfisípò
allot (v)
pín
fífún
allotment (n)
ìpín
pípín
allow (v)
gba-laye
jẹ
gba-fun
jẹki
allowance (n) (permit)
ohun tí a yọ̀da
alloy (n)
àdàlù
ìbàjẹ́
allure (v)
tàn
fà-lọ
fà-láìyà
ally (n)
onígbèjà
almighty (adj)
olúdùmarè
alágbára jùlọ
almond (n)
irú èkùrọ́ òyìnbó kan
almost (adv)
fẹ́rẹ̀
kù díẹ̀
alone (adv)
òn nìkan
gàdàmù
kìkì
along (prep)
pẹ̀lú
lọ́dọ̀
légbèé
aloud (adv)
kíkan
rara
sókè
alphabet (n)
ábídí
alphabetical (adj)
tò l'ábídí lẹ́sẹsẹ
already (adv)
nísìsìyí
íwájú àkókò
na
also (adv)
pẹ̀lú
bẹ́ẹ̀gẹ́gẹ́
ẹ̀wẹ̀
altar (n)
pẹpẹ
ìrúbọ
alter (v)
yípadà
pàrọ̀
tún-e
alteration (n)
ìyípadà
ìpàrọ̀
àtúne
ìyàtọ̀
alternate (adj)
fo ọ̀kan larin
tẹ̀lé lọ́kọ̀kan
alternate (v)
fo ọ̀kan láàrín
alternative (n)
yíyàn
although (conj)
bí ó tilẹ̀jẹ́pé
altitude (n)
gíga
altogether (adv)
pátápátá
gbàà
áká
ráuráu
aluminum (n)
irú irin rírọ̀ kan
always (adv)
nígbàgbogbo
títílái
am (to be)
mbẹ
jẹ́
amateur (n/f)
aláìkọ́ée
akọ́ ohunkóhun láìfi iẹ́ tàrà
amateur (n/m)
aláìkọ́ée
akọ́ ohunkóhun láìfi iẹ́ tàrà
amaze (v)
yàlẹ́nu
hà-e
e-hà
amazement (n)
ìyanu
ìtagìrì
amazing (adj)
tì yanu
ambassador (n)
ikọ̀-ọba
ońọ́ ọba
amber (n) (stone)
ẹ̀yà òkúta iyebíye kan
ambition (n)
ìfọ́ agbára
ífẹ́ ipá
ífẹ́ ohun rere
ọ̀kánjúwà
ambitious (adj)
ní ìfẹ́ agbára
ní ọ̀kánjúwà
onílara
ambulance (n)
ọkọ aláìsàn
ambush (n)
bíba ní bùba
ìdènà
ambush (v)
ba ní bùba
dènà-dè
amend (v)
túne
amendment (n)
ìtúne
àtúne
America (n)
ìlú òkèrè ti
American (adj)
ní ti Amẹ́ríkà
ie ti Amẹ́ríkà
American (n/f)
ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà
American (n/m)
ọmọ ilẹ̀ Amẹ́ríkà
amicable (adj)
bí ọ̀rẹ́
pẹ̀lẹ́tù
nílàjà
ammonia (n)
ìdàlù omi olóòrùn mímú
ìdàlù èlò kíkan
ammunition (n)
ohun ìjà
amnesia (n)
ìgbàgbé
àìlèrántí
amnesty (n)
ìdáríjì ìjọba fún àwọn ẹlẹ́ẹ̀
among (prep)
nínú
láàárín
amount (n)
iye
ample (adj)
tóbi
amplifier (n)
ẹ̀rọìpariwo jọjọ
amplify (v)
pa-ariwo kíkan
amputate (v)
gé kúrò nínú ara
amputation (n)
ìgé kúrò nínú ara
amuse (v)
mú lárayá
iré
pa-lẹ́ẹ̀rín
amusement (n)
ìmúlárayá
ìiré
ìdárayá
amusing (adj)
tí ó panilẹ́ẹ̀rín
anaemic (adj)
àìní ẹ̀jẹ̀ tó lára
analysis (n)
ìtú sí wẹ́wẹ́
ìtúká sí kékèké
analyze (v)
tú sí wẹ́wẹ́
tú palẹ̀
anarchy (n)
ìwà-ní-rúdurùdu
wíwà ní àìlọ́ba
anatomy (n)
ètòìpín ara ènìà
ancestor (n)
babańlá
ancestry (n)
ìbí
ìtilẹ̀ǹde
ìran
babańlá àtí ìyánlá
anchor (n)
ìdákọ̀ró
anchovy (n)
ẹja kékeré oníyọ̀
ancient (adj)
gbó
pẹ̀
àtijọ́
àtaíyébáiyé
and (conj)
on
àti
anesthetic (n)
akunilórun
ògùn ìkinilórun fùn iẹ abẹ
angel (n)
ángẹ́lì
ońẹ́ Ọlọ́run
màlekà
anger (n)
ìbínú
írúnú
angle (n) (corner)
igun
angry (adj)
bínú
mú-bínú
animal (n)
ẹran
ẹ̀dá
ẹlẹ̀ẹ̀mí
animate (v)
ìdárayá
animation (n)
dídárayá
animosity (n)
ìrira
ìbínú
ankle (n)
kókósẹ̀
ọrùn-ẹsẹ̀
annex (n) (building)
ìsọpọ̀mọ́
àfikún ilé
ìdàpọ̀
annihilate (v)
pa-rẹ́
sọ-dasán
sọ-dòfo
parun
annihilation (n)
ìparẹ́
ìsọdasán
ìsọdòfo
àkúrun
anniversary (n)
àjọdún
àyájọ́
announce (v)
kéde
filọ̀
sọ nígbangba
múhìnwá
announcement (n)
ìfilọ̀
ìkéde
announcer (n/f)
akéde
announcer (n/m)
akéde
annoy (v)
dánúbí
mú-bínú
yọ-lẹ́nu
kọ́-lóró
annoyance (n)
ìmúnúbí
ìtô
ìyọnu
annoying (adj)
dídánúbí
annual (adj)
lọ́dọdún
kádún
annually (adv)
lọ́dọdún
annul (v)
pa-rẹ́
mú-kúrò
sọ di òfo
annulment (n)
píparẹ́
ìpatì
ìparẹ́
anonymous (adj)
láìlórúkọ
láìmọ̀
another (adj)
òmíràn
answer (n)
ìdáhùn
ìfèsì
èsì
answer (v)
dá-lóhùn
fèsì
answerable (adj)
íe dálóhùn
ant (n)
èrà
ẹ̀rùn
antagonism (n)
ọ̀tá
ti oníjà
antagonize (v)
ìe ọ̀tá
mú-níjà
antelope (n)
èsúró
ẹtù
antenna (n)
ọ̀pá ìgbà àmì sínú rédíò
ohun kékeré méjì ìmoye l'orí àwọn kòkòrò
anthem (n)
orin mímọ́
orin ìyìn
anthill (n)
òkìtì èrà
agìyàn
ọ̀gán
antibiotic (n)
àjẹsára
ògùn ápóró àìsàn
kòkòrò àìsàn
anticipate (v)
retí
e ájú àkókò
fojúsọ́nà
anticipation (n)
ìrètí
ìfojúsọ́nà
ìe ájú àkókò
antidote (n)
ògùn ápóró ọgbẹ́
àpaàgùn
apiwọ
antifreeze (n)
ohun èlò tí ndíwọ́ dídì omi
antique (adj)
nkan ìgbani
nkan ìgbà laílaí
antiquity (n)
ohun àtijọ́
ohun ìgbà laílaí
antiseptic (n)
egbògi ìdíwọ́ bíbàjẹ́ nkan
àpaàgùn
antlers (n)
ìwọ nlá
anus (n)
àmùu
ihò-ìdí
anvil (n)
oobọ
otarogún
anxiety (n)
àìbalẹ̀-ọkàn
hílà-hílò
ájọ̀
àníyàn
anxious (adj)
aájò
àníyàn
any (adj)
èyíkéyìí
anybody (pron)
ẹnikẹ́ni
anyhow (adv)
bótiwùkórí
lọ́nàkọnà
bákan
ekúe
anything (pron)
ohunkóhun
anytime (adv)
nígbàkúùgbà
anyway (adv)
lónákọ́ná
anywhere (adv)
ibikíbi
apart (adj)
lọ́tọ̀
apart (adv)
lápákan
sọ́tọ̀
géde
apartment (n)
ilé àpíngbé
iyàrá
ìyẹ̀wù
ape (n)
ìnọ̀kí
ọ̀bọ
akítì
ẹdun
aperitif (n)
ohun àfitọ́nilẹ́nuwò
onjẹ ìpanu
ónjẹ àmúnúyá
apex (n)
góngó
ónó
apologetic (adj)
kùn fùn ẹ̀bẹ̀
títúbà
apologize (v)
bèbẹ̀
ìpẹ fún
túbà
apology (n)
ẹ̀bẹ̀
ìpẹ
ìtuuba
ìtọrọ àforíjì
apostle (n)
ọmọ ẹ̀hìn
àpóstẹ́lì
òjíẹ́ krístì
apostrophe (n)
irú àmì kan
kọmá olókè
appal (v)
dẹ́rùbà
fòlaíyà
já-laíyà
appalling (adj)
ti fífòyà
burújù
ìbanilêrù
apparatus (n)
ohun èlò
apparent (adj)
hàn gbángbá
apparently (adv)
àé
appeal (n) (law)
ìfilọ̀
ìbéèrè
ẹ̀bẹ̀
ẹjọ́ àpètúnpè
appeal (v) (law)
bẹ̀bẹ̀
fi ọ̀ràn lọ̀
appealing (adj)
fífi ọ̀ràn lọ̀
bíbẹ̀bẹ̀
appear (v)
hàn
farahàn
yọjáde
yọjú
appearance (n)
ìfarahàn
ìyọjáde
ìrísí
wíwò
appease (v)
tù-nínú
ìpẹ-fún
pẹtùsí
appendix (n) (body)
ẹ̀yà-ara kán
ẹ̀yà ìfun
appendix (n) (book)
àkọkún
ìfikún
appetite (n)
ebi pípani
ìfẹ́ láti jẹun
applaud (v)
pàtẹ́wọ́
yìn nípa pípàtẹ́wọ́
applause (n)
ìyìn
apple (n)
èso òro òyìnbó
appliance (n)
ohun èlò
applicable (adj)
tí a lè filò
ìbámu
ìbálọ
applicant (n/f)
ẹnití ó e ìbèrè fún nkan
olùbérè nkan
ẹní nwáẹ́
applicant (n/m)
ẹnití ó e ìbèrè fún nkan
application (n)
ìfọkànsí
ìfisí
ìwé ìbèrè fún ǹkan
apply (v)
fisí
bèrè fún
filọ̀
appoint (v)
pinnu
yà-sọ́tọ̀
yàn
appointment (n)
ìpinnu
ìpàdé
yíyàn
appraisal (n)
dídíyelé
appraise (v)
díyelé
appreciate (v)
mọyì
kúnlójú
mọ rírì
appreciation (n)
mímọye
mímọrírì
mímọyì
ìkúnlójú
apprehend (v)
dì mú
gbá-mú
bẹ̀rù
fòiyà
apprehension (n)
ìbẹ̀rù
ìdìmú
ìfòyà
apprehensive (adj)
tìbẹ̀rù
e iyèméjì
tìfòyà
apprentice (n/f)
olùkọ́ẹ́
ẹnití nkọ́ẹ́
ọmọ iẹ́
apprentice (n/m)
olùkọ́ẹ́
ẹnití nkọ́ẹ́
ọmọ iẹ́
apprenticeship (n)
ìgbà ìkọ́ẹ́
approach (n)
ìsúnmọ́
approach (v)
súnmọ́
approachable (adj)
eé súnmọ́
appropriate (adj)
wọ̀
yẹ
bámu
kongẹ́
approval (n)
ìfohùnsí
ìlóhùnsí
ìdùnwọ́
approve (v)
nínú dídùn sí
dùnmọ́
approximate (adj)
dédé
approximately (adv)
e dédé
apricot (n)
irú èso òyìnbó kan
April (n)
où kẹ́rin ọdún
apron (n)
bàntẹ́
sálà
tòbí
aptitude (n)
yíyẹ
ìmúra
aquarium (n)
ilé ìtọ́jú àwọn ẹja
aqueduct (n)
ojú-ìsàn tí a là fún omi
arbitrary (adj)
láìe ìbéèrè
láìwádìí
arbitrate (v)
làjà
dúbú-ọ̀ràn
arbitration (n)
gbígbọ́
dídájọ́fún
ìlàjà
ìlàníjà
arbitrator (n/f)
adúbú ọ̀ràn
onílàjà
arbitrator (n/m)
adúbú ọ̀ràn
onílàjà
arc (n)
apá kan àyíká
arch (n)
bìrìkìtì
archaelogist (n/f)
ẹnití nwúlẹ̀ láti e ìwádìí ohun ìgbà láíláí
archaelogist (n/m)
ẹnití nwúlẹ̀ láti e ìwádìí ohun ìgbà láíláí
archaeology (n)
ẹ̀kọ́ nípa ìhúlẹ̀ ohun ìgbà láíláí
archaic (adj)
ti àtijọ́
tí kò wúlò
archer (n)
atọfà
ẹnití ntá ọfà
archery (n)
ọfà
archipelago (n)
àgbájọ-erékùu
architect (n)
ayàwòrán ilé
ọ̀gá ilé kíkọ́
ọ̀mọlé
alápẹrẹ ilé
architecture (n)
ilé kíkọ́ alárà
ẹ̀kọ́ ilékíkọ́
archives (n)
àwọn ìwé ìlú
àkójọpọ̀ ìwé ìrántí
archway (n)
ẹnu ọ̀nà ìwọ̀lú
area (n)
agbègbè
ilë
arena (n)
gbagede eré tàbí ìjà
ibi eré
oju ìgbà
argue (v)
jiyàn
àròyé
làdì
argument (n)
ìjiyàn
ìàròyé
ìlàdì
iyàn-jíjà
argumentative (adj)
jíjiyàn
arid (adj)
gbígbẹ
láìlẹ́tù
láìlọ́rà
arise (v)
dìde
yọ jáde
farahàn
arithmetic (n)
ẹ̀kọ́-ìirò
ìirò-owó
arm (n)
ápá
arm (v)
dìhámóra ogun
hámọ́ra
armament (n)
ọ̀wọ́ ogun
àwọn tí ó múra ogun
armchair (n)
àga alápá ńlá
àga onírọ́pá
armed (adj)
híhámọ́ra ogun
armful (adj)
kún dé òkè
ti ẹ̀kún apá
ẹ̀kún
armistice (n)
ìlàjà
ìparí ogun
ìdáwọ́ ogun dúró
armor (n)
ìhámọ́ra
armory (n)
ilé ìpamọ́ ìhámọ́ra
armpit (n)
ihò abíyá
arms (n)
ohun èlò ogun
army (n)
ọmọ ogun
aroma (n)
òórùn dídùn
òórùn tí nta sánsán
òórùn tí ntafírí
around (adv)
yípo
káríkárí
around (prep)
yíká
kiri
arouse (v)
jí lójú orun
tají
arrange (v)
tò lẹ́sẹsẹ
fi sí ètò
arrangement (n)
e ètò
ìtò lẹ́sẹsẹ
ìfisí ètò
array (n)
ìwọ
ìọ̀ọ́
ètò
arrears (n)
àjẹsílẹ̀
tẹ̀hìn
arrest (n)
ìdádúró
ìdìmú
ìdílọ́wọ́
mímú
arrest (v)
dádúró
dì-mú
dìílọ́wọ́
arrival (n)
dídé
àtidé
bíbọ̀
àbọ̀
arrive (v)
ìpadàbọ̀
bọ̀
arrogance (n)
ìgberaga
ìrera
àdábọwọ́
arrogant (adv)
gbéraga
arrow (n)
ọfà
arsenal (n)
ibi ìrọ ohun ìjagun
àkójọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìjagun
arson (n)
ẹ̀ẹ̀
ilé kíkun
fífilé jóná
ìtinábọlé
art (n)
ọnà
ìmọẹ́ ọnà
ẹ̀kọ́
ọgbọ́n
artery (n)
àpò ẹ̀jẹ̀
ian ìmẹ̀jẹ̀ àn káàkiri ara
arthritis (n)
làkúrègbé
article (n)
nkan
ohun kan
articulate (v)
sọ kétékété
artificial (adj)
ìfi ọgbọ́n e
tí a fi ọgbọ́n e
tí kì íe ti èdá
artillery (n)
ilé ìpamọ́ èròjà
ìbọn nlá
àgbá
artist (n/f)
oníọnà
òyàwòrán
artist (n/m)
oníọnà
òyàwòrán
artistic (adj)
iẹ́ ọnà
ti ọlọ́gbọ́n
as (adv)
gẹ́gẹ́bí
bíti
bíótijẹ́pé
as (prep)
gẹ́gẹ́bí
ascend (v)
gòkè
gùn
pọ́n
ash (n)
érú
ashamed (adj)
tijú
ashore (adv)
nílẹ̀
sílẹ̀
lébùúté
ashtray (n)
àwo érú sìgá
Asia (n)
ilẹ̀ Éíà
ilẹ̀ ìwọ̀̀ òrùn
Asian (adj)
ti ilẹ̀ Éíà
nìlẹ̀ Éíà
Asian (n/f)
ọmọ ilẹ̀ Éíà
Asian (n/m)
ọmọ ilẹ̀ Éíà
ask (v)
bérè
tọrọ
bi-lẹ́rè
asleep (adv)
sùn
rẹ́jú
ojú orun
asparagus (n)
ohun ọ̀gbìn òyìnbó
asphalt (n)
títì ọlọ́dà
asphyxiate (v)
fúnilọ́rùnpa
asphyxiation (n)
ìfúnilọ́rùnpa
aspirin (n)
ògùn
assassin (n/f)
apànìà
assassin (n/m)
apànìà
assassinate (v)
pànìà
pa
lunipa
assassination (n)
ìpànìà
pípa ọba ìjòyè tàbí òè ìlú
assault (n)
ìjà ìpanilára
ìkọlù
assault (v)
panilára
kọlù
assemble (v)
tò mọ́ ara wọn
kójọ
gbárajọ
assembly (n)
àpéjọ
assert (v)
tẹnumô
sọ
assertion (n)
ọ̀rọ̀
ìtẹnumọ́
assertive (adj)
onítẹnumọ́
ọlọ́rọ̀
assess (v)
yẹ̀wò
fún
assessment (n)
ìyẹ̀wò
iye tí a bù
iye tí a pín
bíbù
assets (n) (property)
dúkìyá
assign (v)
rán níẹ́
yàn-sílẹ̀
fi-lélọ́wọ́
assignment (n)
iẹ ọ̀nà
ìyànsílẹ̀
ìfilélọ́wọ́
iẹ́
assist (v)
rànlọ́wọ́
kùnlọ́wọ́
assistance (n)
ìrànlọ́wọ́
assistant (n/f)
olùrànlọ́wọ́
aranilọ́wọ́
assistant (n/m)
olùrànlọ́wọ́
aranilọ́wọ́
associate (n/f)
igbá-kejì
ẹlẹ́gbẹ́
ẹgbẹ́
ẹnìkejì ẹni
associate (n/m)
igbá-kejì
ẹlẹ́gbẹ́
ẹgbẹ́
ẹnìkejì ẹni
association (n)
ẹgbé
ìbálòpọ̀
assorted (adj)
ìyàsọ́tọ̀
assortment (n)
oríiríi
ìyàsọ́tọ̀tọ̀
assume (v)
e-bí
gbà-ebí
dáwọ́lé
rò-pé
assumption (n)
ìebí
gbígbà
ìdáwọ́lé
ríròpé
assurance (n)
ìdánilójú
ìgbẹ́kẹ̀lé
ìfọwọ́sọ̀yàfún
assure (v)
dálójú
tẹnumọ́
sọdájú
múdájú
asterisk (n)
irú àmì kan
àmì àkíyèsí
asthma (n)
ikọ́-fe
astonishing (adj)
níyanilẹ́nu
astonishment (n)
ohun ìyàlẹ́nu
ìyanu
ìtagìrì
astound (v)
yàlẹ́nu
astray (adv)
ìnà
yapa
ako
kúrò lójú ọ̀nà
astrology (n)
ìfiràwọ̀ àyẹ̀wò
nípa ìràwọ̀
ọ̀rọ̀ ìsálú-ọ̀run
astronaut (n/f)
ẹnití nwọ inú sánmà lọ e ìwádi àwọn ìràwọ̀ tí nyí òòrùn ká
astronaut (n/m)
ẹnití nwọ inú sánmà lọ e ìwádi àwọn ìràwọ̀ tí nyí òòrùn ká
astronomy (n)
ẹ̀kọ́ nípa àwọn ìràwọ̀
ìmọ ìràwọ̀
asylum (n)
ibi àbò
ilé ìwòsàn àwọn asínwín tàbí adẹ́tẹ̀
at (prep)
níbí
atheism (n)
ìhìn àìgbàgbọ́ pé Ọlọ́run mbẹ
atheist (n/f)
aláìgbàgbọ́ pé Ọlọ́run mbẹ
atheist (n/m)
aláìgbàgbọ́ pé Ọlọ́run mbẹ
athlete (n/f)
oníjàkadì
ẹnití nsáré ìje
athlete (n/m)
oníjàkadì
ẹnití nsáré ìje
atlas (n)
àwòràn ayé
ìwé àwòràn ìgbélé
atmosphere (n)
òfúrufú
àyíká
atom (n)
ẹ̀rún kíkíní
fínrín
atomic (adj)
ti ẹ̀rún kíkíní
attach (v)
so-mọ́
dàpọ̀mọ́
faramọ́
fimọ́
attack (n) (medical)
ìkọlù àrùn
attack (n) (military)
ìjagun
ojú ìjà
attack (v)
kọ-lù
dojúkọ
fìjà fún
attempt (n)
ìgbìyànjú
ìgbìdánwò
ìdánwò
ìe fitafita
attempt (v)
gbidánwò
dánwò
kọlù
dáwọ́lé
attend (v)
fiyèsí
dúrótì
dúrodè
forísí
attendance (n)
ìfiyèsí
ìfetísílẹ̀
ìdúrótì
attendant (n/f)
ọmọ-ọ̀dọ̀
onítọ̀ọ́jú
ọmọ-ẹ̀hìn
attendant (n/m)
ọmọ-ọ̀dọ̀
onítọ̀ọ́jú
ọmọ-ẹ̀hìn
attention (n)
ìfojúsí
ìfetísílẹ̀
ìfarabalẹ̀
attentive (adj)
ìfetísí
attest (v)
jẹ́rìí sí
attic (n)
òkè àjà
attitude (n)
ìwà híhù
ìdúró sí
ìwà
ìwo
attorney (n/f)
agbẹjọ́rò
aojú ẹni lábẹ́ òfin
onítọ́jú ohun ẹni
attorney (n/m)
agbẹjọ́rò
aojú ẹni lábẹ́ òfin
onítọ́jú ohun ẹni
attract (v)
fà-mọ́ra
fà-lọ́kàn
attraction (n) (physical)
òfà
òkùnfà
ìfàmọ́ra
ìfàlọ́kàn
attractive (adj)
dára láti wò
tí nfa ni mọ́ra
tí ó wuni
ẹlẹ́wà
auction (n)
ọjà gbànjo
ọjà títà àdíjerà
audience (n)
àpéjọ ọ̀pọ̀ ènìà
awòran
olùwòran
audit (v)
àyẹ̀wò ìwé owó
ìjẹ́rí ìwé ìirò owó
audition (n)
ìdánwò àfẹnukà, àfohùnkọ tàbí àfarae
auditorium (n)
gbàngàn òwòrán
gbàngàn
augment (v)
sọdi púpọ̀
mú pọ̀sí
dàgbàsi
fikún
August (n)
où kẹjọ̀ọ́ ọdún
aunt (n/fa)
arábìnrin bàbá
aunt (n/mo)
arábìnrin ìyá
Australia (n)
ìlú Ọsitrélìà
authentic (adj)
òdodo
tòótô
ojúlówó
authenticate (v)
fi ẹ̀rí ládìí
author (n/f)
olùpilẹ̀ẹ̀
òǹkọ̀wé
author (n/m)
olùpilẹ̀ẹ̀
òǹkọ̀wé
authorities (n)
àwọn alágbára òfin
àwọn àláẹ̀ẹ
àwọn alágbára
authority (n)
agbára à
agbára òfin
agbára
authorization (n)
à
fífún lágbára
fífúnlá
ìpalá
authorize (v)
fúnlá
jẹ́
fún lágbára
autograph (n)
fífi ọwọ́ ẹni kọ sílẹ̀
ífẹwọ́ẹnikọsílẹ̀
automate (v)
fi ẹ̀rọ tì síwájú
fún lágbára
fẹ̀rọí
automatic (adj)
ohun tí niẹ́ fún ararẹ̀
ohun tí ntìkararẹ̀ iẹ́
automation (n)
ìfi ẹ̀rọ tí nkan síwájú
fi ẹ̀rọ́ fún lágbára ìrìn
automobile (n)
mọ́tọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́
autonomous (adj)
láìgbáralé
láìní alákoso
láìfàrakọ́
èyítí ne ìlú fún ara rẹ̀
autonomy (n)
àìgbáralé
e alákoso
láìfarakọ
agbára àti máa e ìlú fún ara ẹni
autopsy (n)
ètò ìewàdí ohun tí ó pa ni
ìèwádì ewu tí ó pani
autumn (n)
àkókò ìkórè
ìgbà ogbò
availability (n)
ìanfàní
lílérè
available (adj)
lérè
yẹ
ànfàní
tí a lè rì gbà
avalanche (n)
ìdógìdì olójijì ohunkóhun
avenge (v)
gbẹ̀sán
kọ̀yà
avenue (n)
ọ̀nà gbọrọ
ojú ọ̀nà
àyè
average (adj)
níwọ̀n
average (n)
ìwọ̀túnwọ̀nsì
aversion (n)
ìrira
àiní ìfêsí
avert (v)
mú-kúrò
dá-dúró
yí-padà
aviation (n)
ọhun nípa íe àti wíwa ọkọ̀ òfúrufú
avid (adj) (enjoyable)
ìgbádùn
avoid (v)
yẹra fún
bìlà-fún
yàgò-fún
gáfárà-fún
avoidable (adj)
ohun ìọ́ra fún
yíyẹra-fún
avoidance (n)
ọ́ra
yíyẹra
await (v)
dúró dè
retí
múra sílẹ̀
awake (adj)
ìtají
awake (v)
jí lójú orun
tají
award (n)
ẹ̀bùn
èrè
award (v)
pín fún
e ìdájọ́ fún
aware (adj)
mọ̀
fura
kíyèsí
awareness (n)
ìfura
àkíyèsí
ìmö
away (adv)
kúrò
kálọ
jìnnà
awful (adj)
búrújù
lẹ́rù
lọ́wọ̀
burú
awkward (adj) (clumsy)
àinílárí
wúru-wùru
àìrọrùn
awning (n)
àtíbàbà
axe (n)
àáké
ẹdùn
axis (n)
ọ̀pá tàbí ilà ìlàrín tíí nkan yí
axle (n)
ọ̀pá onírin tíí mú kẹ̀kẹ́ rìn
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com