© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com
D

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

dad (n)
bàbá
dagger (n)
öb÷ olújúméjì
idà kúkurú
daily (adj)
lójojúmô
ojojúmô
níjôgbogbo
dairy (n)
ibi ìfúnwàrà
dam (n)
«í«e önà omi
dídarí omi «í«àn
damage (n)
òfò
ìbàjê
àdánù
ìfarapa
jàmbá
damp (adj)
öririn
òtútù
ìkúku
ògìnnìtìn
dance (n)
ijó
dance (v)
dancer (n/f)
oníjó
dancer (n/m)
oníjó
danger (n)
ìjàmbá
ewu
dangerous (adj)
léwu
ní ìjàmbá
dark (adj)
«ú
«ókùnkùn
àìmòye
darken (v)
«ú òkùnkùn
«e àìmòye
darkness (n)
òkùnkùn
àìmòye
data (n)
ëkô
ìwífún
àkójô èdè fáyëwò
date (n) (fruit)
èso öp÷ dídùn
date (n) (time)
àkókò
æjô tí nkan «÷lë
dative (n)
irú ìlò gírámà kan
daughter (n)
æmæ obìnrin
daughter-in-law (n)
ìyàwó æmæ ÷ni
dawn (n)
àárö kùtù
kùtù-kùtù
àfëmôjúmô
æyê
dawn (v)
môlë
bërësí fi ara hàn
day (n)
æjô
ösán
dead (adj)
láìlêmìí
di òkú
deadly (adj)
tí nmú ikú báni
pípani
deaf (adj)
dití
deal (n)
ìpín
ì«òwò
ìbá«e
irú igi kan
dealings (n)
ìbálò
ìbá«òwò
ìbá«e
dean (n) (school)
olórí ilé ëkô
death (n)
ikú
debate (n)
ìjiyàn
àríyànjiyàn
iyànjíjà
debate (v)
jiyàn
sæ àsæyé
debris (n)
pàntí
debt (n)
gbèsè
decade (n)
ædún mêwàá
mêwàá
decay (n)
ìbàjê
rírà
decay (v)
bàjê
deceased (adj)
÷nití ó ti kú
÷ni kòsí
ologbé
àìsí
deceit (n)
ëtàn
mêëwá
àrékendá
èrú
ìrêj÷
deceitful (adj)
lêtàn
nírëêj÷
deceive (v)
tàn-j÷
«ì-lônà
«e-àgálámàn«à sí
December (n)
o«ù Kejìlá ædún
ìpárí ædún
decency (n)
ìwà yíy÷
títô
fífínjú
fónífóní
decent (adj)
yíy÷
ëtô
ìfínjú
níparamô
deception (n)
ëtàn
èrú
àbòsí
haramù
ìrêj÷
deceptive (adj)
lêërú
nítànj÷
nírëj÷
decide (v)
pinnu
parí rë
fi ìgbà sí
fi òpin sí
decision (n)
ìpinnu
ìfòpin-sí
deck (n)
it÷ apako
ækö
declaration (n)
ìt÷numô
wíwí
sísæ
declare (v)
t÷numô
kéde
decline (n)
ìdínkù
ìparí
kíkö
decline (v) (fall)
decline (v) (refuse)
decode (v)
táká
yanjú
làdí
decontaminate (v)
tún«e
«e àtún«e
yæ ohun ìbàjê kúrò
decorate (v)
«e lô«ô
dálôlá
sìw÷-fún
«elêwà
decoration (n)
ohun ö«ô
ìwë
decrease (v)
dínkù
rëhin
fà-sêhìn
dedicate (v)
fi sôtö
yà-sôtö
yà sí mímô
fi ìwé kíkô júbà ènìà
dedication (n)
ìfisôtö
ìyàsímímô
deduct (v)
mú-kúrò
yæ-kúrò
yæ-jáde
deduction (n) (removal)
ìmúkúrò
ìyækúrò
deduction (n) (thought)
ìyæjáde
ëkô
àfàyæ
deed (n) (action)
ì«e
ìlò
deed (n) (document)
ìwé ìní
deep (adj)
jijin
jinle
deep (adv)
jíjinlë
wíwæra
kára
púpö
deer (n)
àgbörín
ìgalà
egbin
deface (v)
pa-rê
bà-jê
bàlójújê
default (n)
àbùkù
ìkunà
àìlè«e nkan
default (v)
«e àbùkù
defeat (n)
ì«égun
ìbì«ubú
ìparun
defeat (v)
ségun
bì-«ubu
pa-run
lésá
defect (n)
abàwon
àbùkù
defective (adj)
níàbawæn
ní àbùkù
defence (n)
àbò
asà
defend (v)
gbèjà
dábòbò
«e odi fún
defendant (n/f)
enití a pè lêjô
defendant (n/m)
enití a pè lêjô
defensive (adj)
láìlègbëbi
tí «e ìgbèjà ara ÷ni nígbàkúùgbà
tí kò mæ ëbi gbà
defer (v)
súnsíwájú
dá-dúró
fà-sêhìn
fifalë
deference (n)
ìyìn
öwö
ìböwö
ìforíbalë
ìjúbà
defiance (n)
ìfòlêy÷
ìpèníjà
deficiency (n) (fault)
àbùkù
ë«ë
deficiency (n) (lack)
àìpé
àbùkù
deficit (n)
àìpé
àbùkù
define (v)
àsæyé
túmö
definite (adj)
dájú
tóyanjú
pàtó
pàtàkì
definitely (adv)
dájúdájú
pàtàkì
láláìyë
definition (n)
ìtumö
oríkì
deformed (adj)
lábùkù
ìbàlêwàjê
ríræ
defraud (v)
rê-jë
tànj÷
«e-èrú
degrading (adj)
tí ó yë nípò
tí ó rë-sílë
ìrësílë
degree (n) (temperature)
ìwön òtútù tàbí oru
delay (v)
dá-dúró
yë-sêhìn
fà-sêhìn
jáfara
fifalë
delegate (n/f)
a«ojú-÷ni
a«oju
delegate (n/m)
a«ojú-÷ni
a«oju
delegation (n)
÷gbê a«ojú
deliberate (adj)
àmöômö «e
àgbìmö«e
létòlétò
deliberately (adv)
àmöômö
delicate (adj)
«êlêg÷
dára
delicious (adj)
dùn
aládùn
delightful (adj)
ládùn
dídùn
deliver (v)
gbà
jö-lôwô
gbà-sílë
bímæ
delivery (n)
ìbôlôwô
ìjölôwô
ìbímæ
demand (n)
ìbéèrè
demand (v)
béèrè
fagbára béèrè
demanding (adj)
líle
«í«òro
ní «òro
tí nse ìbérè
democracy (n)
ìjæba ìgbàtí agbára wà lôwô àwæn ènìà
ìjæba ti àwn ènìà
democratic (adj)
ti ìjæba àwæn ènìà
ti ìjæba ìgbàtí agbára wà lôwô àwæn ènìà
demon (n)
è«ù
iwin
abili
demonstrate (v)
fi hàn
làdì
«e hàn
demonstration (n)
ìfihàn
iìàdì
ìfihàn ní gbangba
ì«ehanni
demote (v)
fàsêhìn láti ipò nla
rësílë
dá padà sêhìn
den (n) (animal)
ihò
denial (n)
sísê
ìfidù
kíkö
denounce (v)
báwí
jêrí sí
kìlö
dense (adj)
ki
nípæn
dídì
dent (n)
ìtësínú
dentist (n/f)
oní«ègùn ehín
dentist (n/m)
oní«ègùn ehín
deny (v)
fidù
kö fún
gbónu
depart (v)
kúrò
kángárá
department (n)
apá
ìsö
sàkaaní
departure (n)
ilæ kurò
iku
atilæ
àyún
depend (v)
gbêkëlê
gbáralé
gbíyelé
gbójúlé
dependable (adj)
tí ó «eé gbêkëlê
tí ó «eê gbáralé
dependence (n)
ìgbáralé
ìgbêkëlê
ìgbôjúlé
ìwàníkáwô
dependent (adj)
tí ó gbêkëlé ÷lòmíràn
ní ti àgbàtôjú
ní ti àgbàbô
nípa wíwà níkàwô
deploy (v)
rán læ
tú-sílë
deport (v)
lé kúrò ní ìlú
wàlæ
hùwà
deportation (n)
lílé kúrò ní ìlú
wíwàlæ
deposit (n) (bank)
ohun ìdógó
àdáwin
deposit (v) (bank)
fi dógó
fi «úra
depot (n)
ile ì«úra
ibi ìpamô
èbúté ækö
èbúté èrò
depression (n) (mental)
ìrësílë
ìrëwësí
ìdorí kodò
deprive (v)
gbà lôwô ÷ni
rô lóyè
gbàloyè
depth (n)
jíjìn
ìjìnlë
ìbú
descendant (n)
æmæ
àtëlé
describe (v)
förö «àp÷r÷
sæ bí ó ti rí
júwe
«àpèjúwe
description (n)
àp÷r÷
ìsàp÷r÷
àpèjúwe
desert (n)
aginjù
a«álë
desert (v)
kö sílè
fi-sílè
yæ sílè
desertion (n)
ìkösílë
ìyæsílè
deserve (v)
tô-sí
design (n)
ìrò
ìmò
àp÷r÷
àpéjúwe
àwòrán
design (v)
«e àp÷r÷
designate (v)
pè lórúkæ
sàmì sí
yàn
designer (n/f)
÷nití n«e àp÷r÷
ayàwòrán
designer (n/m)
÷nití n«e àp÷r÷
ayàwòrán
desire (n)
ifë
ìwù
desire (v)
beere
desk (n)
àpótí ìwé
obití á ti nköwé
desolate (adj)
tí nsæ dahoro
despair (n)
àìnírètí
despair (v)
«æ-ìrètí nù
«ò«ì
desperate (adj)
láìnírètí
láìdábà
fi àáké kô rí
gbé ikú tà
despise (v)
kêgàn
fi «ësín
«ata
pëgàn
despite (prep)
bíótilèjêpé
dessert (n)
àkàrà dídùn
àj÷kêhìn
onj÷ dídùn àj÷kêhìn onje
destination (n) (journey)
òpin ìrìnàjò
ìdélé
destiny (n)
opin nkan
opin ÷nikan
àyànmô- ìpin
destitute (adj)
láìní
kíkösílë
ní tálákà
àbòsí
ò«ì
destroy (v)
parun
rún
sìbárá
panirun
parê
destroyer (n) (ship)
ækö ælô«÷
destruction (n)
ìparun
ìparê
ìsædòfo
ìsædasàn
detach (v)
yà sôtö
wôn-nù
detachable (adj)
tí a lè yà sótò
lôtö
detail (n)
rírò lôkökan
detain (v)
dá-dúró
tì-môlé
detect (v)
wá-rí
jádi
detection (n)
ìwá-rí
ihù sílè-ìfihàn
detective (n/f)
ælôpà inu
öt÷lëmúyê
detective (n/m)
ælôpà inu
öt÷lëmúyê
detention (n)
ìdáni dúró
deter (v) (prevent)
dádúró
dáiyàfò
detergent (n)
æ«÷
determination (n)
ìpinnu
determine (v)
pinnu
fæwô-söiyà
ròpin
determined (adj)
tí ó pinnu
tí ó fæwô-söyà
detonate (v)
tú-sílë
bê pëlú ariwo nlá
detour (n)
gbígba önà míràn
devaluation (n)
ìsædòfo
ìsædìbàjê
ìgékù
devalue (v)
sæ-dòfo
fi ÷nu tê
sæ-dìbàjê
«o di yëyè
gé kù
devastate (v)
parun
mú «òfò
bàjê
develop (v)
tú-sílè
mú dagba
gberu
development (n)
ìdágba
ìhù
ìgbérú
deviate (v)
yànà
yapa
«ìnà
sápákan
«è yapa
deviation (n)
ìyà kúrò lónà
ì«ìnà
ìyà-sápákan
ìyapa
device (n)
ìmò i«e
ërö
ægbôn
ipèté
devil (n)
è«ù
ènìà búburú
òrì«à
devise (v)
«ë rö
dámòràn
devote (v)
ijà sótö
yà sí mímó
fi pèrí
devotion (n)
ìfækànsìn
ìgbájúmô
àdúrà
dew (n)
ìrì
eeni
diabetes (n)
atögbé
àrùn tí nmú ni tö nígbàgbogbo
diabetic (adj)
alátögbé
diagnose (v)
«e ìwádìí àìsàn
diagnosis (n)
ìmö ìdí àìsàn
ìmö
ìmö«òro-òõkàwè
ìmö ìdí àì«I«ê ohun
diagram (n)
àwòrán atæka
dial (n)
ojú agogo
dial (v)
yí ojú agogo
dialect (n)
ëka-èdè
orí«i ìyàtö nínú èdè kannà
diameter (n)
ìwön ìlà òpindópin
diamond (n)
òkúta oníyebíye jùlæ
diaper (n)
a«æ ìgbàdí æmæwô
diarrhea (n)
ìgbê
gbúrú
íi«unú
àrùn«ù
inú «í«ú gbúrù
diary (n)
ìwé ìtòì«÷lë ojojúmô
dice (n)
ìrêwêlê
èlò ìta têtê
dictate (v)
pà«÷
pè àpèkæ
dictation (n)
àpèkæ
à«÷
dictator (n)
÷nití ó ní agbára láti «e ìlú lí önà tí ó wùú
÷nití ó ní agbára à«÷
dictatorship (n)
níní ágbára à«÷
ìfagbára à«÷ «e ìlú lí önà tí ó wu ni
dictionary (n)
ìwé à«àjæ örö
ìwé ìtúmö örö
àtúmö-èdè
die (v)
«aláìsí
diet (n)
onj÷
àìj÷un
ìj÷un níwönba
ìfebipara-÷ni
difference (n)
ìyàtö
ìjiyàn
àìdôgba
ààwö
different (adj)
yàtö
yíyàtö
láìdôgba
difficult (adj)
ní«òro
le
nira
nípönjú
difficulty (n)
í«òro
ìyænu
ìnira
ëtì
wàhálà
dig (v)
walë
wà nílë
wáàdí
digest (v)
da onj÷
tò lês÷s÷
digestion (n)
dída onj÷
títò nkan lês÷s÷
dignity (n)
ælá
ìyìn
ipò ælá
ìgbéga
dilemma (n)
ì«òro ní yíyàn
híhá
ipò èwoniká«e
diligence (n)
ápæn
àìsimi
àì«e mêlê
ësö
diligent (adj)
láìsimi
lápæn
÷lêsö
dilute (v)
fomipò
bomilà
bù-là
dàlù
dimension (n)
títóbi
ìnà
ìbú
ìwön
dine (v)
j÷ún
bù j÷un
dining room (n)
yàrá onj÷
dinner (n)
onj÷ alê
dinosaur (n)
irú ÷ranko nlá àtijó kan
ohun àtijô
ohun ìgbànì
dip (v)
fi-bö
fibomi
diploma (n)
ìwé ìjáde ilé ëkö gíga
ìwé tí àwæn alá«÷ ilé-ëkô gíga fi æwô
diplomat (n/f)
ò«èlú
÷nití n«e alámójútó örö ìlú láti ìlú òkòrè
diplomat (n/m)
ò«èlú
÷nití n«e alámójútó örö ìlú láti ìlú òkòrè
direct (adj)
tàrà
gan
ganran
direct (v)
tô sônà
fönàhàn
«e amönà
tôkasí
júwe
direction (n)
önà
títô
áp÷r÷
àpéjúwe
ìhà
directions (n) (use)
títô
àpéjúwe
ìtôsônà
director (n/f)
afönàhàn
alákoso
director (n/m)
afönàhàn
alákoso
directory (n)
ìwé ìlànà ìsìn
ìwé tí a to orúkæ àwæn tí ngbé ìlú kan àti ibití nwôn ngbé sí
dirt (n)
èérí
êgbin
÷rë
ìgbönsë
dirty (adj)
kún fún èérí
léèrí
lêgbin
àìmô
ríri
disability (n)
àìlágbára
àbö ara
disabled (adj)
alábö ara
disadvantage (n)
àìní ànfàní
òfo
ìpalára
disagree (v)
«àìrê
«àìbámu
yàtö
daya
disagreement (n)
ìyàtö
ìyapa
ìjà
disappear (v)
farasin
kúrò lójú
mú mô ni lójú
disappearance (n)
ìfarasin
ìmúmô ni lójú
disappoint (v)
dá lára
mú lí ojú òfo
sé-hùn
y÷ àdéhùn
disappointing (adj)
ti ìmúlë- mófo
ìdálára
disappointment (n)
ìmófo
ìdálára
àìrí ohun tí ækàn fê
ìrètí tàbí ìgbêkëlé tí ó «áki
disapproval (n)
kíkö
áìfê
àìgbà
disapprove (v)
«aláìfê
«àìgbà
disarm (v)
gba agbára kúrò
gbà lóhun ìjà
já ohun ìjà gbà
disarmament (n)
gbígba agbára kúrò
disaster (n)
ewu nlá
ìjábà
àjálù
jàmbá
disastrous (adj)
ohun eléwu
ní jàmbá
disband (v)
túká
disbelief (n)
àìgbàgbô
discharge (n) (medical)
æyún
ètútú
discharge (v)
yæ kúrò ní i«ê
sæ di òmìnira
yìnbæn
«i«ê
san
disciple (n)
æmæ ëhìn
discipline (n)
ëtô
ìkóníjanu
ìbáwí
disclose (v)
fi hàn
disclosure (n)
ìfihàn
ì«ípayá
discomfort (n)
ìnira
ìrora
àìní àláfíà
ìbànújê
àìtùnínú
disconnect (v)
yæ kúrò
pín níyà
discontinue (v)
fi sílë
dá dúró
«àlàfo
discount (n)
ìyækúrò
ìdínwókù
ìdínkù
owó
discourage (v)
dàìyàfò
«àìgbàníyànjú
rôlápá
tô ní sùúrù
discover (v)
wá-rí
jágbôn
discovery (n)
àwárí
ìjágbön
discreet (adj)
gbôn
ní«æra
lóye
farabalë
discrepancy (n)
ìyàtö
àìbá dôgba
discretion (n)
ogbôn inú
ægbôn
òye
lákàyè
discriminate (v)
fìyàtö sí
sàmìsí
yànjù
mêyà
discrimination (n)
÷lêyàmêyà
àmì ötö
ìyànjù
ìfì-ìyàtö-sí
discuss (v)
sörölélórí
föröwôrö
sæ kinikini
wádi
jíròrò
discussion (n)
ìjíròrò
ìsörölélórí
ìwadìí
ìföröwôrö
àsögbà örö
disease (n)
àrùn
ökùnrùn
disgrace (n)
ìdójútì
ëgàn
ìtìjú
ëtê
ìfi«élêyà
disgraceful (adj)
ohun ìtìjú
tinilójú
láìnítìjú
disguise (v)
pa-radà
disgust (n)
ìrira
sísú
disgusting (adj)
ti ìrira
àìda
àìtô
dish (n)
àwo
àwopôôkô
dishonest (adj)
láì«öôtô
ní makurúrù
ayédèrú
disk (n)
ohun rìbìtì
ojú òòrùn
ojú ohun tí ó tê
àwo roboto/ribiti/rubu tu
dislocate (v)
yë lóríkè
«ínípò
dismantle (v)
tú-palë
tú-kalë
dismiss (v)
lé-lo
yæ kúrò
rán-læ
yæ kúrò ní i«ê
túká
dismissal (n)
ìránlækúrò
ìyæ kúrò nínú i«ê
ìtúká
disobedience (n)
àìgbæràn
àfojúdi
disobedient (adj)
aláìgbæràn
aláfojúdi
disobey (v)
«e àìgbæràn
«àfojúdi
disorder (n)
ìdàrúdàpö
rúdurùdu
àrùn
disperse (v)
túká
fúnká
displace (v)
yë nípò
yí nípò padà
gba ipò
display (n)
eré
à«ehàn
àwòrán
ìpolówó æjà
fádà
display (v)
fi hàn
«í-sílë
polówó æjà
disprove (v)
jiyàn
túká
àìfaramô
dispute (n)
ìjiyàn
àríyànjiyàn
áwö
asö
æpê-àlàiyé
dispute (v)
jiyàn sí
disrespectful (adj)
àinít÷ríba
àìböwöfún
àìbælá-fún
disrupt (v)
dàrú
disruption (n)
ìdàrù
ìdíwô
ìdálôwôdúr ó
ìdálônà
dissatisfied (adj)
aláìnít÷lôrùn
dissolve (v)
túká
fòpin sí
distance (n)
önà jínjìn
jíjìnà
önàréré
ìdálë
ìtakété
distant (adj)
jìnà
jìjín
réré
tìnà-réré
lókèrè
distinction (n)
ìyàtö
híhàn gbangba
distinguish (v)
sàmì sí lôtö
«e ìyàtö
fi ara hàn bí olóyè nínú ohunkóhun
distract (v)
pín níyà
dàláàmú
sæ di asínwín
distraction (n)
ìdàmú
gbére-gbère
ìsínwín
distress (n)
ì«ê
ìpônjú
àlusìn
wàhálà
distribute (v)
pínká
pín
fônká
distribution (n)
pínpín nkan
ìpínfúnni
ìfônká
district (n)
àgbègbè
sàkání
ëkún
distrust (n)
àìgbêkëlé
àìfækàn-tàn
àìgbáralé
distrust (v)
«àìgbêkëlé
«àìfækàn- tàn
disturb (v)
yæ-lênu
rú sókè
dí lôwô
disturbance (n)
ìyænu
ariwo
ìrókëk÷
ìdílôwô
ìrúkérudò
ditch (n)
kòtò
yàrà
ögbùn
dive (v)
bê sódo
bê sínú omi
mòòkùn
diver (n/f)
ómöw÷
amòòkùn
wæmiwæmi
diver (n/m)
ómöw÷
amòòkùn
wæmiwæmi
diverse (adj)
yàtö
onírúurú
diversion (n)
eré
ìyàsápákan
divert (v)
yæ-sápákan
yà-sôtö
divide (v)
pín
yà nípá
division (n)
ìyanípá
ìpín
divorce (n)
kíkæ ara tækæ taya
ìkösílë
divorce (v)
kö sílë
dizzy (adj)
lóyì
do (v)
«e
dock (n)
ilé ìkàn ækö
ibití ÷lêjô ndúrú sí rojô ní kóòtù
doctor (n/f) (medical)
oní«ègùn
olóyè nínú orí«ìrí«i ëkô
doctor (n/m) (medical)
oní«ègùn
olóyè nínú orí«ìrí«i ëkô
document (n)
ìwé ërí
ìwé ìrídìí nkan
ìwé à«÷
dog (n)
ajá
doll (n)
ère
æmæ-langi
dolphin (n)
irú ÷ja nlá kan
domestic (adj)
ti ilé
tí a tù lójú
dominant (adj)
tó lágbára lórí
tó borí
tìgàba
dominate (v)
«e olúwa
borí
t÷ gába lé lórí
donate (v)
fún lêbùn
fún lôr÷
donation (n)
ëbùn
ær÷
donkey (n)
kêtêkêtê
door (n)
ìlëkùn
ojú-önà
dormitory (n)
yàrá ìbùsùn ÷nipúpö
ìtê òkú
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com