© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com
G

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

gain (n)
èrè
ànfàní
ìfà
gain (v)
jèrè
rí gbà
rí«e
gallery (n) (art)
ödëdë àwòrán
ödëdë lókè
gamble (v)
ta têtê
gambler (n/f)
onítêtê
atatêtê
gambler (n/m)
onítêtê
atatêtê
game (n)
iré
ì«iré
÷y÷ tí æd÷ pa
gang (n)
÷gbê tí ó sowô pö láti «e õkan
gap (n) (opening)
ihò
ëlà
ìsán
àfo
garage (n)
ilé ìpamô ækö
ilé àtún«e ækö ayôkêlê
garbage (n)
ìdötí
garden (n)
ægbà
gardener (n/f)
olóko
olù«ôgbà
a«ôgbà
gardener (n/m)
olóko
olù«ôgbà
a«ôgbà
gardening (n)
dídá oko
gargle (v)
w÷ önà öfun
tu pùpù
garlic (n)
áyù
gas (n)
epo ækö
isó
afêfê inú
gasmask (n)
ohun ìbomú
gasoline (n)
epo (môtö)
gasp (v)
yanu sílë gba afêfê
fi ìtara fê
h÷r÷huru
gate (n)
÷nu önà òde
ìlëkùn
gateway (n)
àbáwælé
àbáwölú
ìwölú
ojúbodè
gather (v)
kójæ
kópö sí ibìkan
«à jæ
péjæ
gbá-jæ
gathering (n)
ìkójæ
ìkópö sí ibìkan
«à jæ
ìpéjæ
ìgbá-jæ
gauge (n)
öpá ìdíwön
gear (n) (car)
ohun èlò tí nmú ækö rìn
gear (n) (equipment)
ohun èlò
gem (n)
òkúta iyebíye
general (adj)
wôpö
àníkárí
ti gbogbo ènìà
general (n) (military)
olórí ogun
ögágun
generally (adv)
nígbàkúgbà
lákòópö
lákolù
generate (v)
bërë
mú jáde
dá sílë
generation (n)
ìran
ìdàræ
generator (n)
ëræ
ëræ ìdàræ iná mönömônô
generosity (n)
inú rere
ö«ônú
ìlawô
generous (adj)
nínú rere
ö«ônú
nílawô
genitals (n)
bòòkëlë ara ækùnrin tàbí obìnrin
okó àti ÷pön
genius (n)
olóye
amòye
iwin
gentle (adj)
ní ìwà pëlê
«e jêjê
gentleman (n)
bökìní
oníwà rere
gbajúmö
gently (adj)
pësëpësë
pëlêpëlê
ræra
lêsölêsö
kêlêkêl ê
genuine (adj)
lótìítô
láì«ëtàn
ojúlówó
geography (n)
ìwé ìkôni nípa àgbáyé
geology (n)
ëkô ohun inú ilë nísàlë
germ (n)
èèhù
orísun
ìbërë
kòkòrò
gesture (n)
ì«esí
ìwö
get (v)
rígbà
gbà
geyser (n)
orísun omi gbígbóná tí nrú láti inú ilë wá
ghost (n)
ëmí
iwin
òkú
giant (n)
òmìrán
asígbænlë
gift (n)
ëbùn
ær÷
giggle (v)
rín ërín kékeré
gill (n)
ërëkê ÷ja
ìjàgbön
giraffe (n)
********** *
girl (n)
æmæbìnrin
girlfriend (n)
örê obìnrin
give (v)
fi fún
fi bùn
jìn
glacier (n)
yìnyín nlá gbalasa
glad (adj)
«e inúdídùn
glamor (n)
ì«újú
glamorous (adj)
ti ì«újú
glance (n)
ìwò fírí
glance (v)
wò fírí
kófírí
wò wêrê
gland (n)
÷«ê
glare (n)
ìkómönà
ìdánmönà
glass (n) (container)
àwo onídígí
glass (n) (substance)
dígí
ìwògbé
àwòjìji
glasses (n)
dígí ojú
dígí ìríran
awò
ìwojú
glider (n)
ohun ìmúni yô b÷r÷
glisten (v)
tan ìmôlë
global (adj)
ti àgbáyé
ti ilë gbogbo
ti gbogbo ènìà
globe (n)
ì«ù rubutu ayé
ayé
glorify (v)
yìnlógo
«e lógo
yìn
glory (n)
ògo
ìyín
ælá
glossary (n)
ìwé ìtúmö
àsæyé
glossy (adj)
dídán
glove (n)
ìbæwô
glow (v)
gbóná janjan
glue (n)
àte
glue (v)
lë-pö
gnat (n)
kantíkantí
go (v) (foot)
rìn
õ«ó
go (v) (vehicle)
rìn
goal (n) (sport)
òpin ìsúré ìje
goal (n) (target)
òpin
goat (n)
òbúkæ
God (n)
Ælôrun
Olódùmarè
godchild (n/f)
æmæ àbánitôjú nínú ìjæ onígbàgbô
æmæ tí a «e àtìlêhìn fún làkókò ìsàmì
godchild (n/m)
æmæ àbánitôjú nínú ìjæ onígbàgbô
æmæ tí a «e àtìlêhìn fún làkókò ìsàmì
goddess (n)
òrì«à obìnrin
godfather (n)
bàbá tí «e àtìlêhìn æmæ lákókò ìsàmì
godmother (n)
ìyá tí «e àtìlêhìn æmæ lákókò ìsàmì
goggles (n)
dígí ojú
awò
gold (n)
wúrà
ìwóòrò
góòlù
golden (adj)
ti wúrà
oníwúrà
goldfish (n)
÷ja aláwö wúrà
golf (n)
irú eré òyìnbó kan
golf course (n)
ægbà nla gbalasa oníkoríko
golfer (n/f)
eléré
golfer (n/m)
eléré
good (adj)
rere
suwön
dára
goodbye (n) (depart)
ìkíni ti ípínyà
önà re o!
ódìgbò «e o!
goodbye (n) (remain)
òdàbö
goodness (n)
ohun rere
goods (n)
÷rù
ohun ìní
æjà
goodwill (n)
ìfê inú rere
goose (n)
abo pêpêye
pêpêye nlá
gooseberry (n)
irú èso kan
gorge (n)
öfun
àj÷fëyà
àj÷jù
gorgeous (adj)
dídára
híhàn
gorilla (n)
ìnàkí
öbæ ìnökí
gospel (n)
ìhìn rere
ìtàn ìgbê aiyé Jésù
örö òdodo
gossip (n)
örö ëhìn
ìsörö asán
òfófó
ìsækúsæ
èké «í«e
ìtukút u
gossip (v)
sörö ëhìn
sörö asán
«òfófó
sæìsækús æ
govern (v)
jæba
«àkóso
«olórí
«ètôjú
government (n)
ìjæba
àkóso ìlú
governor (n)
alábò ìjæba
alákòóso ìlú
baálë
olórí
gómìnà
ajêlë
grab (v)
já gbà
já lôwó
grace (n)
ore-öfê
ojú rere
ànfàní
graceful (adj)
dídára
lêwà
gracious (adj)
olóre-öfê
aláàánú
grade (n) (level)
ipò
ìtêjú
ìtêb÷r÷
ìdôgba
grade (v) (level)
mú têjú
mú dôgba
gradually (adj)
díëdíë
kërëkërë
graduate (v)
to fínífíní
gba oyè ní ilé ëkô gíga
wön
graduation (n)
ay÷y÷ ìparí ëkö kíkà
graft (n)
àlômô
ìlô ëka sínú igi mìíràn
graft (v)
lômô
grain (n)
wóró irúgbìn kan
ækà
àgbàdo
÷yæ
ìwön
gram (n)
irú ìwön kan
grammar (n)
ìmö ìlò örö dájúdájú
gírámà
grammatical (adj)
ti mímæ ìlò örö dájúdájú
granddaughter (n)
æmæ æmæ lobìnrin
grandfather (n/fa)
bàba bàbá
baba ñlá (bàbá)
grandfather (n/mo)
bàbá ìyá
baba ñlá (ìyá)
grandmother (n/fa)
ìyá bàbá ÷ni
ìyá ñlá (bàbá)
grandmother (n/mo)
ìyá ìya êni
ìyá ñlá (ìyá)
grandson (n)
æmæ æmæ lôkùnrin
granite (n)
òkúta akæ dúdú
grant (n)
ëbun fún I«ê «í«e
ohun tí a fifúnni
grant (v)
ffún
fi jíõkí
gbà
grape (n)
èso àjara
grapefruit (n)
òrombó nlá
graph (n)
àwòrán ìwön
grasp (v)
dìmú
fæwô gbá
lóyèe rë
grass (n)
koríko
grasshopper (n)
÷lêñgà
grateful (adj)
lôpë
more
gratitude (n)
ìdúpë
ìmære
grave (n)
ìbòji
isà òkú
gravel (n)
òkúta wêwê
òkúta wêrê
yanrìn
gravestone (n)
òkúta orí ìbòji
graveyard (n)
ìt÷ òkú
gravity (n)
ìwà àgbà
ìjìnlë õkan
ibú
gravy (n)
omi æbë
omitoro
graze (v) (animal)
j÷ koríko
grease (n)
örá
greasy (adj)
kún fún örá
ælôràá
great (adj)
olókìkí
tóbi
ñlá
great grandfather (n/fa)
bàba bàbánlá
great grandfather (n/mo)
bàba ìyáñlá
great grandmother (n/fa)
ìya bàbánlá
great grandmother (n/mo)
ìya ìyánlá
greatness (n)
títóbi
greed (n)
ìwæra
ojúkòkòrò
awun
greedy (adj)
níwæra
lójúkòkòrò
láwun
green (adj)
aláwö ewéko
aláwö öbë-òdò
àìpôn
àìdë
tútù
æb÷dò
greenhouse (n)
ilé ìtôjú ohun ögbìn
greet (v)
yömô
greeting (n)
ìkíni
ìyömôní
grenade (n)
ohun èlò ìjagun
÷tù ìfæwôjù
grey (adj)
tí ó lí àwö dúdú fêrê
grief (n)
ìbanújê
ìkáànú
ëdùn
grievance (n)
ohun ìbanújê
ëdùn
ohun tí ó mú ìbínújê
grieve (v)
bànínújê
dùn
mú ní kêdùn
grill (v)
fìró ëmí ÷ni
dánwò
yan onj÷ lórí iná
grim (adj)
korò
rorò
grime (n)
èérí
grin (n)
ërín àìdénú
grin (v)
rêërín akæ
rêërín ëgàn
grind (v)
pôn
grip (n)
ìgbámú
ìgbæwô
grip (v)
gbámú
dìmú «in«in
groan (n)
ìkérora
gbígbin
groan (v)
kérora
kédàárò
gbin
groceries (n)
æjà
èèlò
groin (n)
kòtò itan
groom (n)
apoko ÷«in
olùtôjú ÷«in
ækæ- ìyàwó
groove (n)
ihò ìtëbö
ground (n)
ilë
ìdílé
ìpìlë
orísun
groundwork (n)
ìpìlë
group (n)
àkójæpö
ìdìpö
òkìtì
group (v)
kójæpö
dìpö
grove (n)
igbó kékeré
igbó «uru
grow (v)
so
dàgbà
growl (v)
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com