© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

U
udder (n)
æmú ÷ranko
æmú màálù
ugly (adj)
burêwà
lábùkù
láìlêwà
ulcer (n)
egbò
oju/ojuju tí ñrà
ultimate (adj)
tí ó gbëhìn
tí ó jìnà jùlæ
tí ó pin sí
umbrella (n)
agbòrùn
agbòjò
unarmed (adj)
láìmúra ìjà
láìmúra ogun
láìdi ìhámôra ogun
unauthorized (adj)
láìní à«÷
tì a kò tíì fi à«÷ fún
unavoidable (adj)
láìlèyëkúrò
láìlèyësílë
unaware (adj)
láìròtêlë
lójijì
láìmö
unbearable (adj)
tí a kò lè gbà
tí a kò lè faradà
unbelievable (adj)
áìgbàgbô
uncertain (adj)
láìdánilójú
láìlègbêkëlé
níyèméjì
uncle (n/fa)
arákùnrin bàbá
uncle (n/mo)
arákùnrin ìyá
unclear (adj)
láìdá«áká
uncomfortable (adj)
láìrærùn
uncommon (adj)
láìwôpö
láì«öpö
láì«egbà kúgbà
unconditional (adj)
ti aláìwön
láìkayelé
láìjêtiwíwön
unconscious (adj)
láìmö nínú
láìlérò
unconsciously (adv)
láláìmö nínú
láláìlérò
uncontrollable (adj)
tí a kò lè kó ní ìjanu
láìlèkóníjan u
under (prep)
lábê
nísàlë
undercurrent (n)
èrò àìsætí tí ñdarí ìpinnu
underestimate (v)
«e àìkàkún
underground (adj)
ìsàlë ilë
abê ilë
underground (n) (subway)
ækö-ilë
ækö-abêlë
rélùwe
underline (v)
fa ilà sí labê
sàmì ìfiyèsí örö
undermine (v)
pa ìpilë run
jìn lêsë
wà nísàlë
underneath (adv)
nísàlë
labê
underneath (prep)
abê
underpass (n)
önà abê títì
understand (v)
gbédè
understandable (adj)
ti mímö
ti yíyé
understanding (adj)
ti òye
understatement (n)
àìwítán
undertake (v)
dáwôlé
undertaking (n)
ohun ìdáwôlé
underwater (adj)
lábê omi
nínú omi
underwear (n)
àwötêlë
undesirable (adj)
àìwuni
tí kò wuni
tí a kò fê ní
undiscovered (adj)
tí kò tí jágbôn
undivided (adj)
láìpín
láìyanipa
lòdidi
ní píye
àìyà
undress (v)
bô «æ
bô-lá«æ
bôrasílë
bôra
uneasy (adj)
láìrærùn
láìfækànbalë
uneducated (adj)
láìlêköô
unemployed (adj)
aláìní«ê lôwô
aláìní«êlápá
unemployment (n)
láláìní«ê lôwô
uneven (adj)
láìtêjú
láìdôgba
unexpected (adj)
láìròtêlë
lójijì
láìretí
àkæsëbá
ëbùrúb ú
unfair (adj)
láìtô
láì«òótö
láì«etàrà
unfaithful (adj)
láì«òótö
láì«òdodo
unfamiliar (adj)
láìfaramô
láìmö
láìmölára
tí a kò mö dáradára
unfinished (adj)
láì«etán
láìparí
láì«epé
unfit (adj) (thing)
láìy÷
láìtô
láìwö
unfold (v) (paper)
«í-sílë
unforgettable (adj)
láìlègbàgbé
unforgivable (adj)
láìlèdáríjì
láìlèfijì
unfortunate (adj) (person)
láìlóríire
lórí búburú
unfortunately (adv)
ó«eniláànú ú
unfriendly (adj)
láì«örè
láì«eun
láì«ojú rere
láìnífë ènìà
ungrateful (adj)
láìmöre
láìlôpê
unhappy (adj)
láìnínúdídù n
láìní ànfàní
unharmed (adj)
láìpalára
láìléwu
unhealthy (adj)
láìnílera
láìlera
láìlágbára
unification (n)
ì«ökan
ìdàpö
ìrêpö
uniform (n)
a«æ ÷gbê kan
ì«ökan
unify (v)
sæ di ökan
«e-sôkan
«e lôkan
unimaginable (adj)
tí kò «eé rò
tí kò «eê gbèrò
unimportant (adj)
láìwíwo
láì«e pàtàkì
uninhabited (adj)
láìjêgbígbé
láì«eégbé
unintentional (adj)
láìmömôö« e
àìpète
union (n)
ìdàpö«ökan
ì«ökan
ìrêpö ÷gbê
ìgbêyàwó
ìgbépö
unique (adj)
làilêgbê
làilékejì
unit (n)
ökan
÷nìkan
unite (v)
so-pö
dàpö
«ökan
parapô
rêmô
united (adj)
áso-pö
ìdàpö
ìrêmô
unity (n)
sísopö
dìdàpö
rìrêmô
universal (adj)
àì«ebìkan
tí ó wôpö
ti ilè gbogbo
ti gbogbo ènìà
universe (n)
ayé
gbogbo ëdá
àgbáyé
university (n)
ilé ëkô gíga
yunifásítì
unjust (adj)
láì«òótô
unjustifiable (adj)
ti a kò lè dáralé
unjustified (adj)
láìnídìí
unkind (adj)
láìnínúre
láì«eun
láì«ojúrere
ní ìkà
unknown (adj)
láìmö
àwámáridìí
unlawful (adj)
lòdì sófin
unless (conj)
bíkò«epé
àyà«ebí
àfibí
bóyá
àfi
unlikely (adj)
láìjêbêë
unload (v) (vehicle)
sæ ÷rù kalë
unlock (v) (door)
«í
fi kôkôrô «í
unlucky (adj)
láìlóríre
unnatural (adj)
lòdì sí ìwà ëdá
láìbá ìwà ëdá mu
àbàmì
unnecessary (adj)
láìy÷
tí ó lè «e aláìní
unpack (v)
tú ÷rú
unpleasant (adj)
láìlàádùn
láìwù
unqualified (adj)
láìlóye
láìní ìmö
unreal (adj)
tí kì í«e òtítô
onítànj÷
÷lêtàn
unreasonable (adj)
lòdì sí ìrònú
tí kò wö lójú
unrest (n)
àisimi
unscrew (v)
«í
unsociable (adj)
làíkêgbé
àìtúraká sí ènìà
unstable (adj)
láìfi ÷së múlë
ni riru
láìmú ara dúró
unsuccessful (adj)
láìyege
unsuitable (adj)
làíly÷
láìbámu
tí kò wö
unsure (adj)
láìdánilójú
láìlègbêkëlé
níyèméjì
unthinkable (adj)
láì«eérò
láìtô
láìy÷
untidy (adj)
wúru-wùru
untie (v)
until (prep)
títí
untrue (adj)
irô
unused (adj)
láìlò
tí a kò ìtí lò
unusual (adj)
láì«e nígbàkúgbà
láìríbê nígàgbogbo
unwilling (adj)
láìní ìfê
tìkö
láìfê
láì«ètara
láfeku« e
unwritten (adj)
láìköwé
tí a ò ko kô sílë
up (adv)
sókè
lókè
up (prep)
lórí
upon (prep)
lórí
sórí
upper (adj)
lókè
lékè
gajù ní ipò
ní önà
uprising (n)
àìsimi ìlú
ötë
ìkö ìsìn amönà
upset (v) (person)
dà-láàmú
upstairs (adv)
lókè
upwards (adv)
lókè
sókè
urge (n)
rírö
bíbë
ìt÷numô
urge (v)
t÷numô
sún lati «e nkan
urgency (n)
líle
ohun pàtàkì
kíkánjú
kánjú
urgent (adj)
le
kunkun
pàtàkì
níkàánjú
urine (n)
ìtö
urn (n)
kòtopó
àgo rìbìtì onírin
us (pron)
wa
use (n)
ìlò
ìhùsí
use (v)
hù-sí
mú-«i«ê
useful (adj)
wúlò
«ànfàní
lérè
nílárí
useless (adj)
áìwúlò
áìnílárí
user (n/f)
÷nití ñlo õkan
user (n/m)
÷nití ñlo õkan
usual (adj)
àtëhìnwá
usually (adv)
àtëhìnwá
utensil (n)
ohun èlò
uterus (n)
àpò ìyè æmæ nínú oyún
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com