© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com
Y

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

yacht (n)
ọkọ̀ ojú omi fún fàájì
yard (n) (area)
àgbàlá
yawn (n)
yíyán
yawn (v)
yán
year (n)
ọdún
oṣù méjìlá
yeast (n)
ìwúkàrà
ọ̀ṣẹ̀
yell (v)
ké ramúramù
kọ
yellow (adj)
pupa rúsúrúsú
bí àwọ̀ ìyeyè
yes (n) (response)
ẹn
bẹ́ẹ̀ni
òótọ́
yesterday (adv)
àná
lánàá
yet (adv)
síbẹ̀
síbẹ̀síbẹ̀
bí ó tilẹ̀ rí bẹ́ẹ̀
yield (n)
èrè
ẹ̀san iṣẹ́
ìkórè
yield (v) (crop)
so
múwá
san
yọdà
yogurt (n)
wàrà
yolk (n) (egg)
pupa ẹyin
you (pron) (familiar)
ìwọ
o
you (pron) (formal)
ẹ̀nyín
nyín
you (pron) (several)
ẹ̀nyin
young (adj)
ṣọmọdé
ṣọ̀tún
ṣọmọdan
your (adj) (one person)
tìrẹ
your (adj) (several)
tiyín
yourself (pron)
ìwọ tìkararẹ
ẹ̀nyin tìkara-nyín
youth (n) (people)
ọ̀dọ́
ọ̀dọ́mọdé
èwe
ọ̀pẹ̀ẹ̀rẹ̀
youth (n) (time)
èwe
youthful (adj)
ti ọ̀dọ́mọdé
nígbà èwe
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com