© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com
Z

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z

zebra (n)
kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà
zero (n) (number)
òfo
zigzag (n)
ségesège
wọ́rọwọ̀rọ
zinc (n)
irin tanganran
zipper (n)
ohun ìdè aṣọ sípù
zone (n)
igun kan nínú ọ̀nà ńlá márùn-ún
ìpínlẹ̀ ayé sí àmurè
zoo (n)
ilé ńlá ìpamọ́ àti ìfihàn onírúurú ẹranko
zoology (n)
ẹ̀kọ́ nípa ìgbésí ayé àti ọ̀nà àwọn ẹranko
© Lorem ipsum dolor sit Nulla in mollit pariatur in, est ut dolor eu eiusmod lorem
yorubadictionary.com