Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

dad (n) bàbá
dagger (n) ọ̀bẹ olójúméjì, idà kúkurú
daily (adj) lójojúmọ́, ojojúmọ́, níjọ́gbogbo
dairy (n) ibi ìfúnwàrà
dam (n) ṣíṣe ọ̀nà omi, dídarí omi ṣíṣàn
damage (n) òfò, ìbàjẹ́, àdánù, ìfarapa, jàmbá
damp (adj) ọ̀ririn, òtútù, ìkúku, ògìnnìtìn
dance (n) ijó
dance (v)
danger (n) ìjàmbá, ewu
dangerous (adj) léwu, ní ìjàmbá
dark (adj) ṣú, ṣókùnkùn, àìmòye
darken (v) ṣú òkùnkùn, ṣe àìmòye
darkness (n) òkùnkùn, àìmòye
data (n) ẹ̀kọ́, ìwífún, àkójọ́ èdè fáyẹ̀wò
date (n) (fruit) èso ọ̀pẹ dídùn
date (n) (time) àkókò, ọjọ́ tí nkan ṣẹlẹ̀
dative (n) irú ìlò gírámà kan
daughter (n) ọmọ obìnrin
daughter-in-law (n) ìyàwó ọmọ ẹni