Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

gain (v) jèrè, rí gbà, ríṣe
gamble (v) ta tẹ́tẹ́
game (n) iré, ìṣiré, ẹyẹ tí ọdẹ pa
gang (n) ẹgbẹ́ tí ó sowọ́ pọ̀ láti ṣe nǹkan
gap (n) (opening) ihò
gate (n) ẹnu ọ̀nà òde, ìlẹ̀kùn
gateway (n) àbáwọlé, àbáwọ̀lú, ìwọ̀lú, ojúbodè
gauge (n) ọ̀pá ìdíwọ̀n
general (v) ögágun
general (v) (military) olórí ogun
giant (n) òmìrán, asígbọnlẹ̀
gift (n) ẹ̀bùn, ọrẹ
girl (n) ọmọbìnrin
girlfriend (n) ọ̀rẹ́ obìnrin
give (v) fi fún, fi bùn, jìn
glad (adj) yọ̀, ṣe inúdídùn
glamor (n) ìṣújú
glance (v) wò fírí, kófírí, wò wẹ́rẹ́
glisten (v) tan ìmọ́lẹ̀
glossy (adj) dídán