Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

table (n) tábílì, ìtẹ́jú, ètò
tablet (n) ohun ìkọ̀wé, wàláà
tack (n) ìṣó kékeré, àdèmọ́lẹ̀ kékeré
tact (n) ọgbọ́n, òye, ìmọ̀
tactful (adj) lọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́
tactical (adj) ìfi ọgbọ́n ẹ̀wẹ́ gbé
tactics (n) ọ̀nà ìjagun ní ilẹ̀ tàbí lórí ókun
tactless (adv) àìlọ́gbọ́n ẹ̀wẹ́
tail (n) ìrù, apá ẹ̀hìn ohunkóhun, ìparí
tailor (n) ọ̀nà ìjagun ní ilẹ̀ tàbí lórí ókun
take (v) (accept) gbà
take (v) (capture)
take (v) (carry) gbé
take (v) (consume) jẹ
take (v) (exam) ṣe
take (v) (obtain) rà, rí-gbà, ní
tale (n) ìtàn, àlọ́
talent (n) ẹ̀bùn Ọlọ́run, ẹ̀bùn àbínibí, iye òṣùwọ̀n kan
talk (n) ọ̀rọ̀ sísọ
talk (v) sọ, sọ̀rọ̀, wí, fọhùn