udder (n)
|
ọmú ẹranko, ọmú màálù |
ugly (adj)
|
burẹ́wà, lábùkù, láìlẹ́wà |
ulcer (n)
|
egbò, oju/ojuju tí ńrà |
underline (v)
|
fa ilà sí labẹ́, sàmì ìfiyèsí ọ̀rọ̀ |
undermine (v)
|
pa ìpilẹ̀ run, jìn lẹ́sẹ̀, wà nísàlẹ̀ |
underneath (adv)
|
nísàlẹ̀, labẹ́ |
underpass (n)
|
ọ̀nà abẹ́ títì |
understand (v)
|
mọ̀, yé, gbédè |
understandable (adj)
|
ti mímọ̀, ti yíyé |
understanding (adj)
|
ti òye |
understatement (n)
|
àìwítán |
undertaking (n)
|
ìdáwọ́lé |
underwater (adj)
|
lábẹ́ omi, nínú omi |
underwear (n)
|
àwọ̀tẹ́lẹ̀ |
undesirable (adj)
|
àìwuni, tí kò wuni, tí a kò fẹ́ ní |
uneducated (adj)
|
láìlẹ́kọ̀ọ́ |
uniform (n)
|
aṣọ ẹgbẹ́ kan, ìṣọ̀kan |
unify (v)
|
sọ di ọ̀kan, ṣe-sọ́kan, ṣe lọ́kan |
university (n)
|
ilé ẹ̀kọ́ gíga, yunifásítì |
unjust (adj)
|
láìṣòótọ́ |