Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

nail (n) (metal) ìṣó
near (adj) ìtòsí, ọ̀dọ̀, súnmọ́ra
neat (adj) fífínjú, já fáfá, afínjú
neck (n) ọrùn, ẹ̀mí
necklace (n) ilẹ̀kẹ̀ ìkárùn
need (n) àìní, àìtó, àbùkù
need (v) ní-lò, fẹ́, fé kù
needle (n) abẹ́rẹ́
needy (adj) aláìní, òtòṣì, tálákà
negotiate (v) ṣe àdéhún, sọ ti ìṣòwò
neighbor (n) aládúgbò, ọmọnìkejì
new (adj) titun, àkọ̀tun
no (adj) agbẹ́dọ̀
no (n) (response) bẹ́ẹ̀kọ́ rárá
noise (n) ariwo, irọ́, òkìkí , àtó
north (n) àríwá, ìhá òkè
nose (n) imú
nostril (n) ihò imú
note (n) (letter) ìwé kúkúrú
note (n) (money) ìwé owó