Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

jacket (n) ẹ̀wù àwọ̀lékè
jail (n) ilé túbú, ilé ẹ̀wọ̀n
jam (n) ((difficulty)) ìṣòro, ìyọnu, ìnira
jam (n) ((jelly)) èso igi tí a ti sè
jammed (adj) fífún pọ̀, títìpọ̀
janitor (n) olùtọ́jú ilé iṣẹ́
January (n) oṣù kíní ọdún
job (n) (task) iṣẹ́ kékeré
job (n) (work) iṣẹ́
joyful (adj) kún fún ayò, ṣàríyá
judge (n) (court) adájọ́, onídájọ́
judge (v) (court) dájọ́, dálẹ́jọ́
judge (v) (estimate) fojú wọ̀n
judgement (n) ìdájọ́
July (n) oṣù keje ọdún
jump (v) fò, bẹ́
June (n) oṣù kẹfà ọdún
justice (n) òtítọ́, òdodo, onídájọ́
justification (n) ìdáláre
justify (v) dá láre