Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

fable (n) ìtàn asán, àlọ́
fabric (n) aṣọ
face (n) ojú
fact (n) àsọdájú, àsọpàtó, ohun ìdájú gan
factory (n) ilé Iṣẹ, ilé òwò, ẹgbẹ́ àwọn oníṣòwò
faculty (n) ìyè, ọgbọ́n orí, ìmọ̀, àṣẹ
fade (v) ṣá, rẹ̀ sílẹ̀, tí, fò
fail (v) bàjẹ́, kùnà, yẹ̀, bàtì, tàsé
faint (adj) àìhàn tán, àìhàn rere
faint (v) dákú, ṣàárẹ̀, ṣojo
fairy (n) àrọ̀nì, egbére, iwin, kúrékùré
fairytale (n) ìtàn àrọ̀nì
faith (n) (belief) ìgbàgbọ́
faith (n) (trust) ìgbàgbọ́, ìgbẹ́kẹ̀lẹ́
faithful (adj) olóòótọ́, olódodo
fake (n) tí kíì ṣe òtítọ́
fake (v) pa-rọ́, ṣe bí ẹnipé, dibọ́n
falcon (n) àṣá
fall (n) (season) ìgbà òtútù
fall (v) ṣubú, bẹ́ sílẹ̀, wó, fàsẹ́hìn, dínkù