Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

abandon (v) fisílẹ̀, kọ̀ sílẹ̀
abbreviate (v) gé kúrú, ṣẹ́kù
abbreviation (n) ìgékúrú, ìṣẹ́kù, àkékúrú, àkọ̀mọ̀nà
abdomen (n) ikùn
abduct (v) gbé sálọ, fà kúrò, ré lọ
abduction (n) ìgbésálọ, ìrélọ
abide (v) bágbé
ability (n) agbára, òye
ablaze (adj) gbiná, jó-wòwò
able (adj) lè, lágbára
abnormal (adj) ṣàjèjì, àbàmì
abolish (v) parẹ́, sọ dasán, sọ dòfo
abortion (n) ṣíṣẹ́ oyún, ìṣẹ́yún, ìṣẹ́nú
abroad (adv) lóde, lẹ́hìn odi, ìdálẹ̀,
abrupt (adj) lójijì, láìmọ̀tẹ́lẹ̀
absence (n) àìsí ńlé
absent (adj) kò sí, kò wà, ṣàìwà
absolutely (adj) pátápátá
absorb (v) fàmu, mì, lá, mu tán
abstain (v) fà sẹ́hìn, takété, sẹ́ ra