Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

mad (adj) ṣiwèrè, bíbàjẹ́ orí, asínwín
maggot (n) ìdin
magic (n) idán
make (v) ṣe, dá
man (n) ọkùnrin, ènìà
many (adj) púpọ̀, pọ́, ọ̀pọ̀lọpọ̀
march (n) oṣù kẹta ọdún
yíyan àwọn ọmọ ogun
march (v) rìn lẹ́sẹsẹ, yan
mare (n) abo ẹ́ṣin
mark (n) àmì orin, àpá
market (n) ọjà
meet (v) pàdé, kò lójú, kò lọ́nà, péjọ
melt (v) yọ́
mend (v) (repair) tún-ṣe, mú-sàn
mercy (n) àánú, ìyọ́nú
mill (n) òlọ̀, ẹ̀rọ
mill (v) lọ̀, rọ
mine field (n) pápá ọta ìhámọ́lẹ̀ fún ìpalára ọ̀tá
mouth (n) ẹnu
music (n) orin