Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

tall (adj) gùn, gíga, gàgàrà
tame (adj) títùlójú, ìtùlójú, tí ojú rẹ̀mọlẹ̀
tank (n) àmù onírin
tank (n) (container) ìkòkò, àmù onírin, odù nlá ìgbómi sí
tank (n) (miitary) àgbá nlá
tanker (n) (ship) ọkọ̀ omi
tap (n) (sink) ìfà omi, èrọ omi
tar (n) ọ̀dà
taste (n) ìtọ́wò
tasteless (adj) (food) láìládùn, tẹ́
tear (n) (break) ìfàya
tear (n) (cry) omije, ẹkún
tear (v) fàya, ya