Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

ache (n) fí-fọ́, ríro
achieve (v) ṣe-tán, ṣe-parí
achievement (n) oríre, àṣetán, àṣeparí
acid (adj) kan, kíkan, mú
acid (n) ògùn kíkan, ògùn mímú
acknowledge (v) jẹ́wọ́, gbà
acknowledgement (n) ìjẹ́wọ́, gbígbà, ìjúbà
acrobat (n) eléré ìtàkìtì, alágèéré
aid (n) ìrànlọ́wọ́, ìtilẹhìn
around (adv) yípo, káríkárí
yípo, káríkárí
augment (v) sọdi púpọ̀mú pọ̀sí dàgbàsi fikún firọ́pọ̀
August (n) oṣù kẹjọ̀ọ́ ọdún
authentic (adj) òdodo, tòótọ́, ojúlówó
authenticate (v) fi ẹ̀rí ládìí
authorities (n) àwọn alágbára òfin, àwọn àláṣẹ̀ẹ, àwọn alágbára
authority (n) agbára àṣẹ, agbára òfin, agbára
authorization (n) àṣẹ, fífún lágbára, fífúnláṣẹ, ìpaláṣẹ
authorize (v) fúnláṣẹ, jẹ́, fún lágbára
autograph (n) fífi ọwọ́ ẹni kọ sílẹ̀, ífẹwọ́enikọsílẹ̀, ìfọwọ́sí
automate (v) fi ẹ̀rọ tì síwájú, fún lágbára, fẹ̀rọṣí