automatic (adj)
|
ohun tí nṣiṣẹ́ fún ararẹ̀, ohun tí ntìkararẹ̀ ṣIṣẹ́ |
automation (n)
|
ìfi ẹ̀rọ tí nkan síwájú, fi ẹ̀rọ́ fún lágbára ìrìn |
automobile (n)
|
mọ́tọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ |
autonomous (adj)
|
láìgbáralé, láìní alákoso, láìfàrakọ́, èyítí nṣe ìlú fún ara rẹ̀ |
autonomy (n)
|
àìgbáralé, ṣe alákoso, láìfarakọ, agbára àti máa ṣe ìlú fún ara ẹni |
autopsy (n)
|
ètò ìṣewàdí ohun tí ó pa ni, ìṣèwádì ewu tí ó pani |
autumn (n)
|
àkókò ìkórè, ìgbà ogbò |
availability (n)
|
ìṣanfàní, lílérè |
available (adj)
|
lérè, yẹ, ṣànfàní, tí a lè rì gbà, tí a lè rí lò |
avalanche (n)
|
ìdógìdì olójijì ohunkóhun |
avenge (v)
|
gbẹ̀sán, kọ̀yà |
avenue (n)
|
ọ̀nà gbọrọ, ojú ọ̀nà, àyè |
average (adj)
|
níwọ̀n |
average (n)
|
ìwọ̀túnwọ̀nsì |
aversion (n)
|
ìrira, àiní ìfẹ́sí |
avert (v)
|
mú-kúrò, dá-dúró, yí-padà |
aviation (n)
|
ọhun nípa ṣíṣe àti wíwa ọkọ́ òfúrufú |
avid (adj)
(enjoyable)
|
ìgbádùn |
avoid (v)
|
yẹra fún, bìlà-fún, yàgò-fún, gáfárà-fún |
avoidable (adj)
|
ohun ìṣọ́ra fún, yíyẹra-fún |