Yorùbá Dictionary .com

Browse Alphabetically

avoidance (n) síṣóra, yíyẹra
await (v) dúró dè, retí, múra sílẹ̀ dè
awake (adj) ìtají
awake (v) jí, jí lójú orun, tají
award (n) ẹ̀bùn, èrè
award (v) pín fún, ṣe ìdájọ́ fún
aware (adj) mọ̀, fura, kíyèsí
awareness (n) ìfura, àkíyèsí, ìmọ̀
away (adv) kúrò, kálọ, jìnnà
awful (adj) búrújù, lẹ́rù, lọ́wọ̀, burú
awkward (adj) (clumsy) àinílárí, wúru-wùru, àìrọrùn
awning (n) àtíbàbà
axe (n) àáké, ẹdùn
axis (n) ọ̀pá tàbí ilà ìlàrín tíí nkan yí
axle (n) ọ̀pá onírin tíí mú kẹ̀kẹ́ rìn